Pólándì

(Àtúnjúwe láti Pólàndì)

Pólàndì en-us-Poland.ogg /ˈpoʊlənd/ (Pólándì: [Polska] error: {{lang}}: text has italic markup (help)), fun ibise gege bi orile-ede Olominira ile Poland (Rzeczpospolita Polska), je orile-ede ni Aarin Europe [6][7] to ni bode mo Jẹ́mánì si iwoorun; Tsek Olominira ati Slofakia si guusu; Ukraine, Belarus ati Lituéníà si ilaorun; ati Okun Baltiki pelu Kaliningrad Oblast, to wa ni Rosia, ni ariwa. Gbogbo ifesi agbegbe ile Poland je 312,679 square kilometres (120,726 sq mi),[3] to so di orile-ede 69th titobijulo ni aye ati ikesan titobijulo ni Europe. Poland ni iye awon eniyan to ju 38 legbegberun lo,[3] eyi so di orile-ede 34th toleniyanjulo ni aye[8] ati ikan ninu awon toleniyanjulo ni Isokan Europe.

Republic of Poland

Rzeczpospolita Polska
Motto: None1
Orin ìyìn: Mazurek Dąbrowskiego
(Dąbrowski's Mazurka)
Ibùdó ilẹ̀  Pólándì  (dark green) – on the European continent  (light green & dark grey) – in the European Union  (light green)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Pólándì  (dark green)

– on the European continent  (light green & dark grey)
– in the European Union  (light green)  —  [Legend]

Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Warsaw
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaPolish2
Orúkọ aráàlúPólàndì
ÌjọbaParliamentary republic
Andrzej Duda
Donald Tusk
Formation
966
July 1, 1569
November 11, 1918
December 31, 1944
• Third Republic
January 30, 1990
Ìtóbi
• Total
312,679 km2 (120,726 sq mi) (70th3)
• Omi (%)
3.07
Alábùgbé
• Jan 2010 estimate
38,533,299[1] [2] (34th)
• December 2007 census
38,116,000[3] (34th)
• Ìdìmọ́ra
122/km2 (316.0/sq mi) (83rd)
GDP (PPP)2008 estimate
• Total
$668.551 billion[4] (21st)
• Per capita
$17,536[4] (50th)
GDP (nominal)2008 estimate
• Total
$527.866 billion[4] (18th)
• Per capita
$13,846[4] (50th)
Gini (2002)34.5
Error: Invalid Gini value
HDI (2007) 0.880[5]
Error: Invalid HDI value · 41st
OwónínáZłoty (PLN)
Ibi àkókòUTC+1 (CET)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+2 (CEST)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù48
Internet TLD.pl
1 See, however, Unofficial mottos of Poland.
2 Although not official languages, Belarusian, Kashubian, Lithuanian and German are used in 20 communal offices.
3 The area of Poland according to the administrative division, as given by the Central Statistical Office, is 312,679 km2 (120,726 sq mi) of which 311,888 km2 (120,421 sq mi) is land area and 791 km2 (305 sq mi) is internal water surface area.[3]
4 The adoption of Christianity in Poland is seen by many Poles, regardless of their religious affiliation or lack thereof, as one of the most significant national historical events; the new religion was used to unify the tribes in the region.

Idasile orile-ede Poland bere pelu Esin Kristi latowo Mieszko I olori ibe, ni odun 966, nigbati orile-ede yi gba gbogbo aye ti Poland gba loni. Ile-Oba Poland je didasile ni 1025, ni odun 1569 o bere long ajosepo pipe pelu Grand Duchy of Lithuania nipa titowobo Isokan ilu Lublin, to sedasile Ajoni Polandi ati Lithuania.

Ajoni yi wo ni 1795, be sini Poland je pipin larin Ile-Oba Prussia, Ile-Oluoba Rosia, ati Austria. Poland pada gba ilominira ni Igba Oselu Keji Poland ni 1918, leyin Ogun Agbaye Akoko, sugbon o je didurolori latowo Jẹ́mánì Nazi ati Isokan Sofieti nigba Ogun Agbaye Keji. Poland pofo emin awon eniyan toju egbegberun 6 lo ninu Ogun Agbaye Keji, o bere lekansi gege bi orile-ede Olominira awon Ara ile Poland larin Blok Ilaorun labe olori Sofieti.

Nigba awon Ijidide odun 1989, ijoba komunisti wolule leyin re Poland di "Oselu Keta Poland" pelu ofin ibagbepo. Poland je orile-ede onisokan, to je idipo awon ipinle merindilogun (Pólándì: [województwo] error: {{lang}}: text has italic markup (help)). Poland je ikan ninu Isokan Europe, NATO, Agbajo awo Orile-ede, Agbajo Idunadura Agbaye, ati Agbajo fun Ifowosowopo Okowo ati Idagbasoke (OECD).

Warsaw


  1. Bank Danych Lokalnych, na dzień 31.12.2012 [1]
  2. "Total population – At 1 January". Eurostat. 2009-01-01. Retrieved 2009-05-27. 
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 "Concise Statistical Yearbook of Poland, 2008" (PDF). Central Statistical Office (Poland). 28 July 2008. Archived (PDF) from the original on 2011-07-14. Retrieved 2008-08-12. 
  4. 4.0 4.1 4.2 4.3 "Poland". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01. 
  5. [2]. The United Nations. Retrieved 05 October 2009.
  6. "Ẹda pamosi" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2009-12-22. Retrieved 2010-04-11. 
  7. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2019-08-18. Retrieved 2010-04-11. 
  8. NationMaster.com 2003–2007, Poland, Facts and figures