Adam Smith (iribomi 16 June 1723 – alaisi 17 July 1790 [OS: 5 June 1723 – 17 July 1790]) je amoye alawujo ati asiwaju ninu eko itokowo oloselu ara Skotlandi. Enikan pataki ninu Olaju Skotlandi, Smith ni o ko iwe The Theory of Moral Sentiments ati An Inquiry into the Nature and Causes of the Wealth of Nations to gbajumo lasan bi The Wealth of Nations, je gbigba bi ise ninla re ati iwe akoko odeoni nipa isiseitokowo. O je ko gbajumo gidigidi be sini yio je ki o nikopa lori isiseitokowo titi doni. Smith je titokasi kakiri gege bi baba isiseitokowo ati iseowoele.

Adam Smith
A sketch of a man facing to the right
OrúkọAdam Smith
Ìbí5 June 1723
Kirkcaldy, Scotland
Aláìsí17 July 1790(1790-07-17) (ọmọ ọdún 67)
Edinburgh, Scotland
ÌgbàClassical economics
(Modern economics)
AgbègbèWestern philosophy
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Classical economics
Ìjẹlógún ganganPolitical philosophy, ethics, economics
Àròwá pàtàkìClassical economics,
modern free market,
division of labour,
the "invisible hand"
Ìtọwọ́bọ̀wé