John Maynard Keynes
John Maynard Keynes, 1st Baron Keynes ( /ˈkeɪnz/ KAYN-z; 5 June 1883 – 21 April 1946), CB, je ara Britani aseoro-okowo ti eroinu re ko ipa pataki lori irojinle ati imuse oro-okowotitobi odeoni, ati awon iselu oro-okowo awon ijoba. O se atunse gidigidi ise tele lori awon ohun toun fa iyipo osowo, o si polongo fun ilo awon eto isenawo ati oro owo lati satunse ipa buburu awon economic ifaseyin oro-okowo ati itelole oro-okowo. Awon eroinu re ni won di pepe fun ile-eko ero toun je oro-okowo Keynes, ati iru awon to wa lati inu re.
Keynesian economics | |
---|---|
Born | Cambridge, England | 5 Oṣù Kẹfà 1883
Died | 21 April 1946 Firle, East Sussex, England | (ọmọ ọdún 62)
Nationality | British |
Field | Political economy, probability |
Alma mater | King's College, Cambridge |
Opposed | Marx · Hayek · Walras · Marshall · Pigou |
Influences | Smith · Ricardo · Hume · Mill · Malthus · Gesell · Moore · Marshall · Wicksell · Robertson |
Influenced | Whitaker · Lynch · Kalecki · Kuznets · Samuelson · Hicks · Shackle · Vickrey · Galbraith · Minsky · Shiller · Stiglitz · Krugman · Roubini |
Contributions | Macroeconomics, Keynesian Economics, Liquidity preference, Spending multiplier, Aggregate Demand-Aggregate Supply model |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |