Ade Adekola (tí a bíi ni ọdún 1966), jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti onímọ̀ nípa oríṣiríṣi ẹ̀kọ́. Àwọn ènìyàn mọ̀ọ́ ṣí oníṣẹ́-ọnà ayàwòrán, olúyàwòran, oníṣẹ́-ọ̀nà ìgbàlódé, àti ọ̀ǹkọ̀wé.[1][2][3][4][5] Ó ń gbé ní ìlú Èkó.[6]

Ade Adekola
Ọjọ́ìbí3 Oṣù Kẹta 1966 (1966-03-03) (ọmọ ọdún 58)
Lomé, Nigeria
Iṣẹ́Multidisciplinary conceptual artist
Gbajúmọ̀ fúnPhotographer, painter, textile artist, writer, digital artist

Wọ́n bí Ade Adekola ni oṣù kẹ̀ta (March) ọjọ́ kẹ̀ta , 1966 ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó l9 sílé ẹ̀kọ́ Architectural Association School of Architecture tí ó wà ní ìlú Lọndọnu ní ọdún 1992 ṣáájú kí ó tó tẹ̀ síwájú nílé ẹ̀kọ́ University ti Manchester. [citation needed][7][8]


Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Dickson (2018-10-26). "Exhibition Detailing History of Lagos Bar Beach Opens Soon". Leadership News - Nigeria News, Breaking News, Politics and more (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-08-08. 
  2. Cotter, Holland (2013-07-04). "‘Go-Slow’: ‘Diaries of Personal and Collective Stagnation in Lagos’" (in en-US). The New York Times. ISSN 0362-4331. https://www.nytimes.com/2013/07/05/arts/design/go-slow-diaries-of-personal-and-collective-stagnation-in-lagos.html. 
  3. Gonzalez, David (2014-10-27). "A Festival of Ideas and Photos in Africa". Lens Blog, The New York Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-02-10. 
  4. Textilforum. Textilforum e.V. Arbeitsgemeinschaft f. Textil, Vereinregister. 1994. pp. 30. https://books.google.com/books?id=rWlWAAAAMAAJ. 
  5. "Wish you were here: fine art photography ... on a postcard – in pictures" (in en-GB). the Guardian. 2020-12-01. ISSN 0261-3077. http://www.theguardian.com/artanddesign/gallery/2020/dec/01/art-on-a-postcard-fine-art-photography-in-pictures. 
  6. "Nse Ikpe-Etim, William Coupon and Nere Teriba in latest Visual Collaborative SDG publication". The Guardian Nigeria News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-03. Archived from the original on 2021-10-30. Retrieved 2023-02-10. 
  7. Adebambo, Adebimpe (2017-01-11). "Stripes, Weaves, and Colours". Omenka Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2023-04-19. Retrieved 2023-02-10. 
  8. O'Mahony, Marle; Braddock, Sarah (1994-09-01) (in en). Textiles and New Technology 2010. Princeton Archit.Press. pp. 42. ISBN 978-3-7608-8434-9. https://books.google.com/books?id=c6kmYQgDG6YC.