Ade Laoye jẹ́ òṣèrébìnrin láti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Pennsylvania State University, níbi tí ó ti kọ́ nípa eré orí-ìtàgé.[2]

Ade Laoye
Fáìlì:Ade Laoye.png
Ọjọ́ìbíDayton, Ohio, United States of America
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaPennsylvania State University
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́2006–present
Notable workKnocking on Heaven's Door

Ade Laoye kọ́kọ́ hàn sí gbàgede nínú fíìmù àgbéléwò Knocking on Heaven's Door láti ọwọ́ Emem Isong. Ade tún hàn nínú Lunchtime Heroes láti ọwọ́ Seyi Babatope àti nínú fíìmù kéékèèké orí Africa Magic, tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Hush láti ọwọ́ Oye Agunbiade.[3] Ade Laoye pẹ̀lú àwọn ògbóǹtarìgì àwọn òṣèrébìnrin mìíràn bíi Kehinde Bankole, Munachi Abii, àti Omowumi Dada, ni Tunde Leye fi hàn pé wọ́n jẹ́ olú ẹ̀dá-ìtàn nínú fíìmù àgbéléwò Finding Hubby.[4] Wọ́n yan Ade Laoye fún àmì-ẹ̀yẹ ti Barrymore Award fún orin kan tí ó kọ ní ilé-iṣẹ́ The Arden Theatre.[5]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe
  • A Naija Christmas (2021)
  • Collision Course (2021 film) (2021)
  • Finding Hubby (2020)[6]
  • Lizard (2020)
  • A second Husband (2020)
  • Walking with Shadows (2019)[7]
  • Oga John (2019)
  • Knockout Blessing (2018)
  • Castle & Castle (2018)
  • You Me Maybe (2017)
  • Hush (2016)[8]
  • Erased (2015)
  • Lunch Time (2015)
  • Dowry (2014)
  • Àyìnlá (Fíìmù Àgbéléwò)

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Bold men get my attention – Ade Laoye, actress, presenter". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-07-15. Retrieved 2021-04-05. 
  2. "I was the drama queen in my family - Ade Laoye". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-12-24. Retrieved 2021-04-05. 
  3. "I was the drama queen in my family - Ade Laoye". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-12-24. Retrieved 2021-04-05. 
  4. "Kehinde Bankole, Munachi Abii, others to star in 'Finding Hubby'". 19 September 2020. 
  5. "Ade Laoye". IMDb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-05. 
  6. "Ade Laoye, Kehinde Bankole, others to star in 'Finding Hubby' screen adaptation". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-09-17. Retrieved 2021-04-23. 
  7. "Ade Laoye Archives". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-04-23. Retrieved 2021-04-23. 
  8. ""Hush" actress talks fears, upcoming projects, winning awards". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-04-17. Archived from the original on 2021-04-23. Retrieved 2021-04-23.