Àyìnlá (Fíìmù Àgbéléwò)
Àyìnlá jẹ́ fíìmù àgbéléwò olókìkí ajẹmórin kan tí ó dá lórí ìtàn ìgbésí aye Àyìnlá Yusuf tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Àyìnlá Ọmọwúrà, olórin Àpàlà tí máníjà rẹ̀ tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Báyéwù gún pa nínú ìjà ilé ọtí ní Ọjọ́ 6, oṣù Èbìbí, Ọdún 1980 ní ìlú Abẹ́òkúta. Fíìmù náà jẹ́ ṣíṣàfihàn ní ọjọ́ 13, Oṣù Okúdù Ọdún 2021 ní Ìlú Èkó, a sì gbé e jáde ní àwọn ilé ìṣàfihàn eré ní ọjọ́ 18, Oṣù Kẹfà, Ọdún 2021. Tunde Kelani ni olùdarí rẹ. Fíìmù náà jẹ́ yíyà pẹ̀lú ìwòye bí ìlú Abẹ́òkutà, ti wọn ya ni Abeokuta, Ìpínlẹ̀ Ògùn ṣe rí ní àwọn ọdún 1970 àti ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ọdún 1980.[2] Lateef Adedimeji ni ó kópa gẹ́gẹ́ bí Àyìnlá, pẹ̀lú àwọn òṣèré bíi Omowumi Dada, Bimbo Manuel, Ade Laoye, Kunle Afolayan, Bimbo Ademoye and Mr Macaroni . Àyìnlá ní fíìmù àgbéléwò pàtàkì akọkọ Kelani láti ìgbà tí ó ti gbé Dazzling Mirage jáde ní Ọdún 2015.[2] Ètò ìsúná fún fíìmù àgbéléwò yìí jé gbígbé jáde gẹ́gẹ́ bí (Àádọ́ta Mílíọnù). ₦50 Million.[3]
Àyìnlá | |
---|---|
Fáìlì:Àwòrán Àlẹ̀mọ́giri Àyinla.jpg | |
Adarí | Tunde Kelani |
Olùgbékalẹ̀ | Jadesola Osiberu |
Àwọn òṣèré | Lateef Adedimeji Omowumi Dada Bimbo Manuel Ade Laoye Kunle Afolayan Bimbo Ademoye Mr Macaroni |
Olùpín | FilmOne |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 110 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | Yoruba |
Ìnáwó | ₦50 Million |
Owó àrígbàwọlé | ₦91,470,900[1] |
Ẹ̀dá-ìtàn
àtúnṣe- Lateef Adédiméjì bíi Ayinla
- Omowumi Dada
- Bimbo Manuel
- Ade Laoye bíi Jaye
- Kunle Afolayan bíi Ajala
- Bimbo Ademoye
- Mr Macaroni bíi Bayewu
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ
àtúnṣeỌdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Olùgbà | Èsì | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2021 | Africa Movie Academy Awards | Best Actor in a Leading Role | Lateef Adedimeji|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [4] | |
Achievement in Cinematography | Ayinla|Gbàá | ||||
Best Film in An African Language|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |||||
Best Nigerian Film|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Tunde Kelani's 'Ayinla' hits N70.5m in box office — one month after release". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-07-21. Retrieved 2021-07-21.
- ↑ 2.0 2.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:0
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:3
- ↑ Banjo, Noah (2021-10-29). "FULL LIST: Ayinla, Omo Ghetto: The Saga bag multiple nominations at AMAA 2021". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 29 October 2021. Retrieved 2021-10-30. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)