Adebisi Agboola (ojoibi 11 August, 1964 ni Ogbomosho) je omo Yoruba ara Amerika onimo mathimatiki to je ojogbon ni Yunifasiti Kalifornia ni Santa Barbara. Agboola gba iwe-eri bachelor ninu mathimatiki lati Yunifasiti Cambridge, Cambridge, Ilegeesi ni 1985, awon iwe-eri master ati dokita lati Yunifasiti Kolumbia, New York ni 1988 ati 1991.

Iwadi re da lori Irojinle Nomba ati arithmetic algebraic geometry.