Adeline Ama Buabeng

Òṣèrébìnrin ilẹ̀ Ghana

Adeline Ama Buabeng, tí àwọn eniyan mọ sí "Aunty Ama", jẹ òṣèré orí itage àti apìtàn ọmọ orilẹ ède Ghánà. O ti n ṣe iṣẹ orí itage fún ọgbọn ọdun, o si ti kópa ni inu ọ̀pọlọpọ oríṣiríṣi iṣẹ ni ilú Ghánà.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Sutherland-Addy, Esi (2002). "Drama in Her Life: Interview with Adeline Ama Buabeng". African Theatre: Women. James Currey Publishers. pp. 66–. ISBN 978-0-85255-596-5. https://books.google.com/books?id=39ZBOA39DgEC&pg=PA66.