Adeniyi Johnson
Adeniyi Johnson tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kejì ọdún 1978 (27th February 1978) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó ti ju ogún ọdún lọ tí ó ti ń ṣeré tíátà, ṣùgbọ́n ìràwọ̀ rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní tàn nígbà tí ó kópa nínú eré orí tẹlifíṣàn kan tí àkọ́lé "Tinsel". Gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, Tóyìn Àìmàkhù ni ìyàwó àkọ́fẹ̀ Adéníyì Johnson, ṣùgbọ́n kò pẹ́ tí ìgbéyàwó wọn foríṣánpọ́n.[1][2] [3]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Ikande, Mary (2017-12-09). "Exploring private life and career of popular Nollywood actor and Tinsel star Adeniyi Johnson". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2020-01-01.
- ↑ "Adeniyi Johnson begs ex-wife Toyin Abraham to sign divorce papers". Premium Times Nigeria. 2018-12-05. Retrieved 2020-01-01.
- ↑ Published (2015-12-15). "Toyin refused to sign our divorce papers, estranged husband, Adeniyi Johnson laments". Punch Newspapers. Retrieved 2020-01-01.