Adeola Fayehun
Adeola Eunice Oladele Fayehun (bíi ni ọjọ́ kẹfà oṣù keje ọdún 1984) jẹ́ ọmọ Nàìjíríà, ó sì jẹ oniroyin tí ó má ń sọ̀rọ̀ nípa àwọn ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ sí àwọn ọmọ ẹ̀yà Áfríkà.[1][2] [3]
Adeola Fayehun | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Adeola Oladele Fayehun 6 Oṣù Keje 1984 Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Eunice Fayehun |
Ẹ̀kọ́ | Olivet College (B.A., 2007) |
Iṣẹ́ | Journalist |
Ìgbà iṣẹ́ | 2011-present |
Gbajúmọ̀ fún | Keeping It Real with Adeola! |
Website | adeolafayehun.com |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Adeola sì Nàìjíríà, òun sì ni àbíkẹ́yìn nínú àwọn ọmọ márùn-ún tí àwọn òbí rẹ bí.[4] Àwọn òbí rẹ ni Rev. Dr. Solomon Ajayi Oladele ati Margaret Ibiladun Oladele. Ní ọdún 2013, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Olivet College ni Michigan ni orile-ede United States of America, nibe sì ni ó ti gboyè nínú ìmọ̀ Mass communications àti Journalism ni ọdún 2007.[5][6] Ní ọdún 2008, ó gboyè masters degree láti ilé ẹ̀kọ́ CUNY Graduate School of Journalism.[7]
Iṣẹ́
àtúnṣeAdeola bẹ́ẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí a gbèrò yín jáde ni CUNY TV.[7] Ní oṣù kokanla ọdún 2011, bẹ́ẹ̀rẹ̀ ètò ìròyìn Keeping it real with Adeola!.[8][9]Ó tún sì ṣé fún ilé iṣẹ́ The Nation tí ó má ń ṣe ìwé ìròyìn ni Nàìjíríà.[10] Óun ló dá African Spotlight kalẹ̀.[11] Ní ọdún 2015, ohùn àti Omoyele Sowore jọ ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nurọ̀ fún olórí orílẹ̀-èdè Zimbabwe, Robert Mugabe, wọn si béèrè pé ìgbà wo ni ó fé fí ipò olórí orílè-èdè sílẹ̀.[12][13][14] Ní ọdún 2013, ó ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nurọ̀ fún olórí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀, Goodluck Jonathan ni ojú títí New York, ó sì béèrè pé kí ni Jonathan ṣe nípa ọ̀rọ̀ àwọn Boko Haram tí ó da ìlú rú.[15] Adeola si ṣé pelu Sahara Reporters, ó sì má ń ba wọn kọ nípa oselu ilé Áfríkà. Ó ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nurọ̀ fún olórí àti igbá kejì olórí orílè-èdè Nàìjíríà ni ọdún 2015.[16][17] Ní ọdún 2011, ó fẹ́ Victor Fayehun ni Nàìjíríà.[18] Òun àti ọkọ rẹ̀ jọ dá KIRWA foundation kalẹ̀ láti lè pèsè fún àwọn tí ó ní àìsàn ni Áfríkà.[19]
Ẹ̀bùn
àtúnṣeYear | Award | Category | Result | |
---|---|---|---|---|
2008 | Foreign Press Association, New York, NY | Outstanding Academic And Professional Achievement | Gbàá | [4] |
2014 | Ethiopian Satellite News Network (ESAT), Washington DC | Excellence In Journalism For Democracy AwardGbàá | [20] | |
2015 | CUNY Graduate School of Journalism | Best One Woman Show | Gbàá | [1] |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Snow, Jackie (9 March 2016). "Meet Adeola, Nigeria's Jon Stewart: An interview with Adeola Fayehun, the host of Nigeria's Keeping It Real with Adeola". Lenny Letter. http://www.lennyletter.com/culture/a295/meet-adeola-nigerias-jon-stewart/. Retrieved 9 March 2016.
- ↑ Ssali, Shaka (13 May 2015). "Straight Talk Africa: Adeola Fayehun, Host of Sahara TV's "Keeping It Real with Adeola"". Voice of America News. http://www.voanews.com/media/video/2766409.html. Retrieved 14 March 2016.
- ↑ "Just in: Adeola of Sahara Reporters quits Sahara TV". Vanguard News. November 1, 2017. Retrieved May 30, 2022.
- ↑ 4.0 4.1 "Scholarship Winners 2008". Foreign Press Association. Archived from the original on 10 March 2016. Retrieved 9 March 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Olivet College to celebrate Founders' Day Feb. 18". Olivet College. 2 February 2015. Archived from the original on 15 March 2016. Retrieved 14 March 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Career Spotlight: Adeola Fayehun, Journalist". Naija Enterprise. 25 November 2015. Retrieved 14 March 2016.
- ↑ 7.0 7.1 Olumhense, Eseosa (24 August 2013). "Meet the Nigerian Face Behind one of Africa's Most Popular News Satires". Premium Times. http://www.premiumtimesng.com/arts-entertainment/143341-meet-the-nigerian-face-behind-one-of-africas-most-popular-news-satires.html. Retrieved 9 March 2016.
- ↑ Oshodi, Darasimi (27 January 2014). "Adeola Fayehun, the 'bad girl' of Nigerian TV". Inspirational Bursts: Darasimi Oshodi. Retrieved 14 March 2016.
- ↑ Ssali, Shaka (5 March 2014). "Straight Talk Africa: Adeola Fayehun, Host of Sahara TV's "Keeping It Real with Adeola"". Voice of America News. https://www.youtube.com/watch?v=Vy8u7YCeR-k. Retrieved 14 March 2016. "Interview starts at 5:14"
- ↑ "Meet the woman who embarrassed Mugabe in Nigeria". Nehanda Radio. 2015-06-02. Retrieved 2017-08-01.
- ↑ "About". African Spotlight. Archived from the original on 9 March 2016. Retrieved 9 March 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Fayehun, Adeola (31 May 2015). "SaharaReporters Crew Encounter With Pres. Robert Mugabe In Nigeria". SaharaTV. Retrieved 9 March 2016.
- ↑ Thamm, Marianne (5 June 2015). "Nigeria's favourite satirist goes global after ambushing Robert Mugabe". Daily Maverick - Guardian Africa network (The Guardian). https://www.theguardian.com/world/2015/jun/05/nigeria-satirist-adeola-fayehun-robert-mugabe-ambush. Retrieved 9 March 2016.
- ↑ Freeman, Colin (3 June 2015). "How a Nigerian television reporter brought Robert Mugabe to account: TV journalist Adeola Fayehun ambushes Zimbabwean leader and asks why him he hasn't stepped down". The Daily Telegraph. https://www.telegraph.co.uk/news/worldnews/africaandindianocean/zimbabwe/11647333/How-a-Nigerian-television-reporter-brought-Robert-Mugabe-to-account.html. Retrieved 9 March 2016.
- ↑ Fayehun, Adeola (24 September 2013). "SaharaTV Interview with Goodluck Jonathan On The Streets Of New York". SaharaTV. Retrieved 9 March 2016.
- ↑ Fayehun, Adeola (29 September 2015). "Adeola Fayehun Interviews President Buhari". SaharaTV. Retrieved 14 March 2016.
- ↑ Fayehun, Adeola (1 June 2015). "SaharaTV Exclusive Interview With Vice President Yemi Osinbajo". SaharaTV. Retrieved 14 March 2016.
- ↑ Adams, Suzanne (February 2011). "Chronicle". FPA News (Foreign Press Association) 237 (93): 4. Archived from the original on 10 March 2016. https://web.archive.org/web/20160310131754/http://www.foreignpressassociation.org/fpa/wp-content/uploads/2011/10/NL_2011_931.pdf. Retrieved 9 March 2016.
- ↑ "About". KIRWA Foundation. Archived from the original on 10 March 2016. Retrieved 9 March 2016.
- ↑ Fikir, Dudi (21 May 2014). "Ethiopia: Adeola speech at ESAT 4th year anniversary". Ethiopian Satellite Television, ESAT. Retrieved 9 March 2016.