Adeyinka Gladys Falusi jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmò ẹ̀jẹ̀ àti omi ara ní Nàìjíríà, òun sì ni olùdarí tẹ́lẹ̀ rí fún ibi ẹ̀kọ́ "Advanced Medical Research and Training, College of Medicine, ti Yunifásítì ìlú Ìbàdàn.[1][2] Ó ní ìmò púpò nínú àwọn àwọn àìsàn ẹ̀jẹ̀ tí ó ń pa ènìyàn lára.[3]

Adeyinka Gladys Falusi
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
PápáHaematology
Molecular genetics
Bioethics
Ilé-ẹ̀kọ́University of Ibadan
Ibi ẹ̀kọ́University of Ibadan
University College Hospital(PhD)
Doctoral advisorGeorge Joseph Folayan Esan
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síL'Oréal-UNESCO Awards for Women in Science
Fellow of the Nigerian Academy of Science

Ìpìlẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Gladys jẹ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Èkìtì, Nàìjíríà, wón to dàgbà ní Efon Alaaye, Ìpínlẹ̀ Èkìtì, Nàìjíríà. Arábìnrin kan (Grace Oladunni Olaniyan, ẹni tí ó ti di Ojogbon Taylor) tí ó ń gbé ní àdúgbò Gladys ni ó mú kí ó kó nípa ìmò Sayensi.[4] Ó kó nípa ìmò Kemistri ní Yunifásítì ìlú Ìbàdàn (UI).[5] Ó tẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú láti kó nípa ẹ̀jẹ̀ àti omi ara ní College of Medicine ti Ibadan.[6][7]

Ìdílé rẹ̀

àtúnṣe

Ọ̀jọ̀gbọ́n Gladys fẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n Abiodun Falusi, ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmò Agricultural Economics, wón bí ọmọ márùn-ún.[8]

Àwọn Ìtókasí

àtúnṣe
  1. "Biography of Adeyinka FALUSI". African Success. November 8, 2009. Archived from the original on 16 March 2014. Retrieved 16 March 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Prof. Adeyinka G. Falusi". SCHAF (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-01-16. Retrieved 2020-05-28. 
  3. "The 2001 L'Oréal Awards for Women in Science with the Support of UNESCO: Exceptional Woman Researchers from Five Continents". UNESCO. 2001. Retrieved 16 March 2014. 
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0
  5. "Financial Aids | University of Ibadan". www.ui.edu.ng. Archived from the original on 2022-09-02. Retrieved 2022-09-02. 
  6. "I almost blew up the laboratory in secondary school —Prof Adeyinka Falusi » Xquisite » Tribune Online". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-01-18. Retrieved 2020-05-30. 
  7. "Professor Adeyinka G. Falusi". Sickle Cell Hope Alive Foundation. Archived from the original on 16 March 2014. Retrieved 16 March 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "Prof. Adeyinka G. Falusi". SCHAF (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-01-16. Retrieved 2020-05-30.