Ado Ahmad Gidan Dabino, MON jẹ́ akọ̀wé èdè Haúsá Nàìjíríà ,[1]Òǹkọ̀wé,Atẹ̀wétà,Oníròyìn, òǹtẹ̀-fíìmù jáde, Akojú fíìmù àti ọ̀ǹseré.[2] Ó kọ eré fún bi ọgbọ̀n ọdún lórí àkorí oríṣiríṣi. Ó ti ṣe àtẹ̀wétà fún ìwé (Nóvẹ̀lì) mẹ́ẹ̀dọ́gún. Ó gba oyè Member of the Order of the Niger (MON) ẹ̀yẹ yìí ní Ọjọ́ kọkàndílọ́gbọ̀n oṣù kẹsàn-án, ọdún 2014 ní ọwọ́ orílé-èdè Nàìjíríà àná Goodluck Ebele Jonathan.[3][4]

Ado Ahmed Gidan Dabino
Gidan Dabino MON
Ọjọ́ ìbí1 Oṣù Kínní 1964 (1964-01-01) (ọmọ ọdún 60)
Iṣẹ́
  • Writer
  • Publisher
  • Producer
  • Director
ÈdèHausa
Notable awardsSee below
Website
gidandabino.com.ng

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Gidan Dabino, Ado Ahmad [WorldCat Identities]". Worlcat. 10 January 2018. 
  2. Kano, Ibrahim Musa Giginyu (2019-08-31). "How Hausa Day was born – Gidan Dabino". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-09-20. 
  3. "LIST OF 2013/2014 NATIONAL HONOURS AWARD RECIPIENTS – spotlight reports". spotlight reports. 29 September 2014. Archived from the original on 1 October 2018. https://web.archive.org/web/20181001070350/http://www.spotlightreports.com.ng/list-20132014-national-honours-award-recipients/. 
  4. "FG releases list of National Award recipients 2013/2014 – Vanguard News". Vanguard News. 18 September 2014. https://www.vanguardngr.com/2014/09/fg-releases-list-national-award-recipients-20132014/.