Goodluck Jonathan

Olóṣèlú

Goodluck Ebele Jonathan (ojoibi 20 November 1957)[1] je oloselu omo ile Naijiria ati Aare orile-ede Naijiria lati May 6, 2010. Ohun ni Igbakeji Aare ile Naijiria si Aare Umaru Musa Yar'Adua ki o to dipo fun gege bi Adipo Aare ni 9 February, 2010 nitori aisan to de Yar'Adua mole. Leyin ti Yar'Adua ku ni May 5, 2010, Jonathan di Aare. Bakanna tele o tun je Gomina ipinle Bayelsa larin 9 December 2005 ati 28 May 2007 ati Igbakeji Gomina ipinle Bayelsa.

Goodluck Jonathan
Goodluck Jonathan World Economic Forum 2013.jpg
President of Nigeria
In office
5 May 2010 – 29 May 2015
Vice PresidentNamadi Sambo
AsíwájúUmaru Yar'Adua
Arọ́pòMuhammadu Buhari
Vice President of Nigeria
In office
29 May 2007 – 5 May 2010
ÀàrẹUmaru Yar'Adua
AsíwájúAtiku Abubakar
Arọ́pòNamadi Sambo
Governor of Bayelsa
In office
9 December 2005 – 29 May 2007
AsíwájúDiepreye Alamieyeseigha
Arọ́pòTimipre Sylva
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Goodluck Ebele Azikiwe Jonathan

20 Oṣù Kọkànlá 1957 (1957-11-20) (ọmọ ọdún 64)
Ogbia, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party
(Àwọn) olólùfẹ́Patience Faka
Alma materUniversity of Port HarcourtÀwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. Lawson Heyford, "Jonathan: A Colossus at 49", The Source (Lagos), 11 December 2006