Afia Schwarzenegger aka Valentina Nana Agyeiwaa tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlá osù kejì ọdún 1982 sí Kumasi, Ghana jẹ́ oluẹda media ni orílẹ̀ èdè Ghana. Òhun ni olóòtú èto Okay FM's morning show Yewo krom and UTV Ghana's Kokooko show. Òhun ni aláṣẹ Schwar TV lórí YouTube ;  àti QAS purified water , olóòtú èto The breakfast show. A yàán gẹ́gẹ́bí aṣojú àwọn aláìníya àti bàbá ní Ghana nípasẹ̀ ẹgbẹ́ Association of Children Homes and Orphanages ní Ghana.  Ó tún jẹ́ olùdásílè Leave2Live foundation, tí ó jẹ́ ẹgbẹ́ tí ó ran àwọn ènìyàn lọ́wọ́ kúrò níbi ìjà ìpáǹle abele. Ó sì jẹ́ oludasile ti Owontaa Street Ministry, ilé iṣẹ́ tí ó sàánú àwọn aláìní ní Ghana Afia tún ṣiṣẹ́ fún TV Africa àti Kasapa FM . Ó di olókìkí nípasẹ̀ èto Afia Schwarzenegger TV tíDeloris Frimpong Manso ṣe àgbékalẹ̀ .

Afia Schwarzenegger
Ọjọ́ìbíỌjọ́ Kẹrìnlá Osù Kejí Ọdún 1982
Kumasi, Ashanti Region
Orílẹ̀-èdèGhanaian
Iṣẹ́Aláwàdà, Olóòtú ètò TV / Radio
TelevisionThe breakfast show Schwar TV,Yewo Krom, Kokooko Show
Àwọn ọmọ3 James Ian Geiling Heerdegan,John Irvin Geiling Heerdegen,Adiepena Geiling Amankona
Parent(s)Augustine Agyei and Grace Achiaa

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe