Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Obokun

Agbegbe Ijoba Ibile Obokun je ijoba ibile ni Ipinle Osun ni Naijiria. Ibujoko re wa ni Ibokun.

Awon ilu ati abule miran nibe tun ni Esa-Oke, Imesi-Ile ati Ora