Agbègbè Apáìwọ̀òrùn Nàìjíríà

Agbègbè Apá-ìwọ̀-oòrùn Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tàbí Western Region fi ìgbà kan jẹ́ apá ìṣèlú ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pẹ̀lú olú-ìlú ní Ìbàdàn. Wọ́n dá a sílẹ̀ ní ọdún 1930 lábẹ́ ìjọba amúnisìn àwọn ará Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, ó sì wà títí di ọdún 1967.

Maapu Agbègbè Apáìwọ̀òrùn Nàìjíríà ni 1965


Àyọkà tó bára mu

àtúnṣe


Ìtọ́kasí

àtúnṣe