Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan

(Àtúnjúwe láti Britani)

Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándì Apáàríwá ti a mo si Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan, UK tabi Britani jẹ́ orílẹ̀-èdè ní Europe. Nínú bodè rẹ̀ ni a ti rí erékùsù Brítánì Olókìkí, apá ìlàoòrùn-àríwá erékùsù Irẹlandi àti ọ̀pọ̀ àwọn erékùsù kékéèké. Irẹlandi Apáàríwá nìkan ni apá Ilẹ̀ọba Ìsọ̀kan tó ní bodè mọ́ oríilẹ̀ pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Irẹlandi.

Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándì Apáàríwá
United Kingdom of Great Britain and Northern Ireland[1]
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto["Dieu et mon droit"] error: {{lang}}: text has italic markup (help)[2]  (French)
"God and my right"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè"God Save the Queen"[3]
Ibùdó ilẹ̀  Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan  (dark green) – on the European continent  (light green & dark grey) – in Isokan Europe  (light green)
Ibùdó ilẹ̀  Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan  (dark green)

– on the European continent  (light green & dark grey)
– in Isokan Europe  (light green)

Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
London
51°30′N 0°7′W / 51.5°N 0.117°W / 51.5; -0.117
Èdè àlòṣiṣẹ́ English[4]
Àwọn èdè dídámọ̀ níbẹ̀ Welsh, Irish, Ulster Scots, Scots, Scottish Gaelic, Cornish[5]
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2001) 92.1% White,
4.00% South Asian, 2.00% Black, 1.20% Mixed Race, 0.80% East Asian and Other
Orúkọ aráàlú Ará Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan
Ìjọba Parliamentary system and Constitutional monarchy
 -  Monarch Queen Elizabeth II
 -  Prime Minister Theresa May MP
Aṣòfin Parliament
 -  Ilé Aṣòfin Àgbà House of Lords
 -  Ilé Aṣòfin Kéreré House of Commons
Formation
 -  Acts of Union 1 May 1707 
 -  Act of Union 1 January 1801 
 -  Anglo-Irish Treaty 12 April 1922 
Ọmọ ẹgbẹ́ EU 1 January 1973
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 244,820 km2 (79th)
94,526 sq mi 
 -  Omi (%) 1.34
Alábùgbé
 -  Ìdíye mid-2006 60,587,300[1] (22nd)
 -  2001 census 58,789,194[2] 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 246/km2 (48th)
637/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2006
 -  Iye lápapọ̀ US$2.270 trillion (6th)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan US$37,328 (13th)
GIO (onípípè) Ìdíye 2007
 -  Àpapọ̀ iye $2.772 trillion (5th)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan US$45,845 (9th)
Gini (2005) 34[3] 
HDI (2005) 0.946 (high) (16th)
Owóníná Pound sterling (£) (GBP)
Àkókò ilẹ̀àmùrè GMT (UTC+0)
 -  Summer (DST) BST (UTC+1)
Àmìọ̀rọ̀ Internet .uk [6]
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 44
Footnotes


Scafells.jpg

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. "UK population grows to 60.6 million". Population Estimates. Office for National Statistics. 2007-08-22. Retrieved 2007-08-22. In mid-2006 the resident population of the UK was 60,587,000. The UK population has increased by 8 per cent since 1971, from 55,928,000. 
  2. Population Estimates at www.statistics.gov.uk
  3. CIA World Factbook[Gini rankings]