Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Aiyedire

(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Aiyedire)

Agbegbe Ijoba Ibile Aiyedire wà ní Ipinle Osun ni orílé-èdè Naijiria. Ibujoko re wa ni Ile-Ogbo.