Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Obokun

(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Obokun)

Agbegbe Ijoba Ibile Obokun je ijoba ibile ni Ipinle Osun ni Naijiria. Ibujoko re wa ni Ibokun.

Awon ilu ati abule miran nibe tun ni Esa-Oke, Imesi-Ile ati Ora