Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ola Oluwa

(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Ola-Oluwa)

Agbegbe Ijoba Ibile Ola Oluwa je ijoba ibile ni Ipinle Osun ni Naijiria. Ibujoko re wa ni Bode Osi.



iṣẹ tó gbajúmọ̀ ni ibile Ola Oluwa je Ise agbe. akomona ibile Ola Oluwa ni apẹrẹ ounjẹ ipinle osun (food basket of Osun state).