Ahmad Abdulhamid Malam Madori

Ahmad Abdulhamid Malam Madori je olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà. Oun ni Seneto lọwọlọwọ to n ṣoju Jigawa North East ni ìpínlè Jigawa ni Sẹnetọ kẹwa labẹ ẹgbẹ All Progressives Congress (APC). [1] [2] [3]

Awọn itọkasi

àtúnṣe