Ìpínlẹ̀ Jigawa
Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà
Ìpínlẹ̀ Jigawa jẹ́ ọkan nínu ìpínlè mẹ́rìndínlógójì orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ yí wà ní apá àríwá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọdún 1991 láti apá ìwọ̀ Oòrùn gúsù Kánò, Jigawa wa ni ààlà tó wà lárin orílẹ̀-èdè Niger ati orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Dutse ni olú ìlú fún Ìpínlẹ̀ náà, tí ósìjẹ́ ìlú tí o tóbi julọ ní Ìpínlẹ̀ Jigawa.
Jigawa | ||
---|---|---|
| ||
Nickname(s): | ||
Location of Jigawa State in Nigeria | ||
Coordinates: 12°00′N 9°45′E / 12.000°N 9.750°ECoordinates: 12°00′N 9°45′E / 12.000°N 9.750°E | ||
Country | Nigeria | |
Date created | 27 August 1991 | |
Capital | Dutse | |
Government | ||
• Governor (List) | Badaru Abubakar (APC) | |
• Deputy Governor (List) | Umar Namadi(APC) | |
• Legislature | Jigawa State House of Assembly | |
• Senators | NE: Ibrahim Hassan Hadejia (APC) NW: Danladi Abdullahi Sankara (APC) S: Mohammed Sabo (APC) | |
• Representatives | List | |
Area | ||
• Total | 23,154 km2 (8,940 sq mi) | |
Area rank | 18th of 36 | |
Population (2006 census) | ||
• Total | 4,361,002 | |
• Rank | 8th of 36 | |
• Density | 190/km2 (490/sq mi) | |
GDP (PPP) | ||
• Year | 2007 | |
• Total | $2.99 billion[1] | |
• Per capita | $673[1] | |
Time zone | UTC+01 (WAT) | |
postal code | 720001 | |
ISO 3166 code | NG-JI | |
HDI (2018) | 0.414[2] low · 33rd of 37 | |
Website | jigawastate.gov.ng |
Awọn èdè
àtúnṣeAwọn orísìrísí èdè tí ó wà ní ìpínlè Jigawa ní Bade, Warji, Duwai. Hausa ati Fula je èdè ti wọn n sọ jù ni ìpínlè Jigawa.[3]
Ijọba Ìbílẹ̀
àtúnṣeAwọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Jigawa jẹ́ mẹ́tàdìnlógbọ̀n. Awọn ná ní:
- Auyo
- Babura
- Biriniwa
- Birnin Kudu
- Buji
- Dutse
- Gagarawa
- Garki
- Gumel
- Guri
- Gwaram
- Gwiwa
- Hadejia
- Jahun
- Kafin Hausa
- Kaugama
- Kazaure
- Kiri Kasama
- Kiyawa
- Maigatari
- Malam Madori
- Miga
- Ringim
- Roni
- Sule Tankarkar
- Taura
- Yankwashi
Ilé ẹ̀kọ́ gíga
àtúnṣe- Federal University Dutse, Jigawa State
- Sule Lamido University, Kafin Hausa, Jigawa State
- Khadija University Majia, Jigawa State
- Jigawa State Institute of Information Technology, Kazaure
- Binyaminu Usman College of Agriculture, Hadejia, Jigawa State.
- Government Science Technical College, Binin Kudu
- Jigawa State Polytechnic Dutse
- Government Science Technical College, Ringim
- Government Technical College, Hadejia
- Kazaure Innovation Institute, Jigawa State
Itokasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "C-GIDD (Canback Global Income Distribution Database)". Canback Dangel. Retrieved 2008-08-20.
- ↑ "Sub-national HDI - Area Database - Global Data Lab". hdi.globaldatalab.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-09-13.
- ↑ "Nigeria". Ethnologue. https://www.ethnologue.com/country/NG.