Ahmed Hassan Barata
Olóṣèlú
Ahmed Hassan Barata jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Gúúsù Adamawa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2011 sí Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1]
Ahmed Hassan Barata | |
---|---|
Aṣojú Guyuk/Shelleng, Ìpínlẹ̀ Adamawa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kékeré | |
In office Oṣù karún Ọdún 1999 – Oṣù karún Ọdún 2003 | |
Aṣojú Gúúsù Adamawa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Oṣù karún Ọdún 2011 | |
Asíwájú | Grace Folashade Bent |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Collated Senate results". INEC. Archived from the original on 2011-04-19. Retrieved 2011-05-06.