Ahmed Hassan Zewail (Lárúbáwá: أحمد حسن زويل‎, Àdàkọ:IPA-arz) (ojoibi February 26, 1946 ni Damanhour, Egypt) je onimo sayensi omo Egypt-Amerika to gba Ebun Nobel ninu Kemistri ni 1999 fun ise re lori isiseogunisejufemto.

Ahmed Hassan Zewail
Portrait of Dr.Ahmed Zewail
Ìbí26 Oṣù Kejì 1946 (1946-02-26) (ọmọ ọdún 78)
Damanhour, Egypt
Ọmọ orílẹ̀-èdèEgyptian, American
PápáChemistry, physics
Ilé-ẹ̀kọ́California Institute of Technology
Ibi ẹ̀kọ́University of Alexandria, University of Pennsylvania
Ó gbajúmọ̀ fúnFemtochemistry
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize for Chemistry (Sweden)(1999)
The Franklin Medal (USA) (1998)
Wolf Prize (Israel) (1993)
Priestley Medal (USA) (2011)