Aisha Salaudeen
Aisha Salaudeen (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹríndínlógbọ̀n oṣù September, ọdún 1994) jẹ́ gbajúgbajà akọ̀ròyìn, ajàfún ẹ̀tọ́ obìnrin, aṣàgbéjáde ìròyìn àti òǹkọ̀wé tó ń ṣiṣẹ́ ní CNN lọ́wọ́lọ́wọ́.[1] Ní oṣù kọkànlá ọdún 2020, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Future Awards Africa Prize fún iṣẹ́ rẹ̀ nínú ìjábọ̀ ìròyìn, àti bí ó ṣe máa ń kọ ìtàn nípa ilẹ̀ Afrika.[2] Wọ́n pè é láti sọ̀rọ̀ ní Ake Arts and Book Festival ní dún 2020.
Aisha Salaudeen | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 26 September 1994 Jos, Plateau State, Nigeria |
Ẹ̀kọ́ | University of Bradford |
Iṣẹ́ | Journalist, producer |
Ìgbà iṣẹ́ | 2017–present |
Gbajúmọ̀ fún | Women advocacy |
Notable work | CNN Al Jazeera The Financial Times Stears Business |
Awards | The Future Awards Africa for Journalism (2020) |
Website | Nana-Aisha lórí Twitter |
Àwọn iṣẹ́ rẹ̀ tó gbòógì
àtúnṣeAwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeOdun | Eye | Ẹka | Abajade | olugba |
---|---|---|---|---|
2020 | The Future Awards Africa | Gbàá | funrararẹ |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Salaudeen, Baliqees (18 December 2020). "15 minutes with Aisha Salaudeen". THE AVALON DAILY (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 23 December 2020. Retrieved 1 March 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Lekan, Otufodurin (28 November 2020). "CNN's Aisha Salaudeen wins The Future Awards Africa Prize for Journalism". Media Career Services (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 28 November 2020. Retrieved 1 March 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Free to read | Single women cannot rent property in Nigeria". www.stearsng.com. 1 February 2019. Retrieved 1 March 2021.
- ↑ Aisha Salaudeen. "This 9-year-old has built more than 30 mobile games". CNN. Retrieved 1 March 2021.
- ↑ Aisha Salaudeen. "The woman risking her life to photograph the forgotten victims of war". CNN. Retrieved 1 March 2021.