Ajílẹ̀ ni a lè pè ní èròjà tí a ṣe yálà nílàna Ìgbàlódé ni tàbí ti àbáléyé tí a wá dá tabí pòó mọ́ ilẹ̀ láti lè jẹ́ kí ilẹ̀ ó ní agbára láti mú ohun ọ̀gbìn jáde dára dára ju t'àtẹ̀yìnwá lọ. A lè ṣe ajílẹ̀ pẹ̀lú àwọn ohun èlò nílé iṣẹ́ ìgbàlódé tàbí kí á ṣe é pẹ̀lú àwọn ohun èlò ìbílẹ̀.[1] Nípa iṣẹ́ ọ̀gbìn ìgbàlódé wọ́n ma ń lo èròjà : nitrogen (N), phosphorus (P), àti potassium (K) tí wọ́n sì ma ń fi èròjà rock flour kun kí ó lè rú gọ́gọ́. Àwọn àgbẹ̀ ma ń po ajílẹ̀ mọ́ iyẹ̀pẹ̀ nípa kí wọ́n wọn sí orí ilẹ̀ tàbí kí pòó mọ́ omi tàbí kí wọ́n fi ọwọ́ pòó mọ́ iyẹ̀pẹ̀.

A farmer spreading manure to improve soil fertility

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Ullmann1