Akademio de Esperanto
Akademio de Esperanto ni, gege bi ibiitakun re se so, ìdìmúlẹ̀ elede alominira ti ise re je lati mu duro ati da abo bo awon opo ede Esperanto ati akoso idagbasoke re. Aba re wa latowo L.L.Zamenhof ni Apejo Kariaye Akoko Esperanto, o si je didasile pelu oruko Lingva Komitato, eyun Igbimo Ede.
Ni 1948 Igbimo Ede ati Akademi darapo lati da Akademio de Esperanto.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |