Akinwunmi Adesina
Akinwumi "Akin" Adesina jẹ́ olókòwò orílè-èdè Nàìjíríà, ẹnití ó ń sìngbà gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ African Development Bank. Ó ti kọ́kọ́ jẹ́ Mínísítà fún ètò-ọ̀gbìn àti ìdàgbàsókè àwọn ìgbèríko.[2] Kí a tó yàn án gẹ́gẹ́ bíi Mínísítà ni 2010, òun ni igbá-kejì Ààrẹ fún ètò-ìmúlò àti àjọṣe pò fún Alliance for a Green Revolution in Africa (AGRA).[3] Wọ́n dìbò yàn án gẹ́gẹ́ bíi Ààrẹ fún African Development Bank ní 2015 wọ́n tún dìbò yàn án ní èkejì ni 2020. Òun ni ọmọ Nàìjíríà àkọ́kọ́ láti wà ní ipò náà.[4]
Akinwumi Adesina | |
---|---|
Akinwumi Adesina in 2014 | |
8th President of the African Development Bank | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 1 September 2015 | |
Asíwájú | Donald Kaberuka |
Nigerian Agriculture Minister | |
In office 2010–2015 | |
Ààrẹ | Goodluck Jonathan |
Asíwájú | Abba Sayyadi Ruma |
Arọ́pò | Audu Ogbeh |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 6 Oṣù Kejì 1960[1] Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Alma mater | University of Ife Purdue University (PhD) |
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ́
àtúnṣeWọ́n bí Adesina fún àgbẹ̀ Nàìjíríà kan ní Ibadan, Oyo state.[5] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ ìgbèríko ó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè láti University of Ife. Òun ni akẹ́kọ̀ọ́ tí a kọ́kọ́ fún ní ipò kíní láti Fáṣítì rẹ. Ó tún tẹ̀síwájú ẹ̀kọ́ rẹ̀ [6] Ó sáré wá sí Nàìjíríà láti gbéyàwó ní í [7] níbi tí ó ti tayọ jùlọ nínú ẹ̀kọ́ fún iṣẹ́ ìwádìí rẹ̀.[8]
Career
àtúnṣeFrom 1990 to 1995, Adesina served as a senior economist at West African Rice Development Association (WARDA) in Bouaké, Ivory Coast.[9] He worked at the Rockefeller Foundation since winning a fellowship from the foundation as a senior scientist in 1988. From 1999 to 2003, he was the representative of the Foundation for the Southern African area.[10] From 2003 to 2008, he was an associate director for food security.[11]
Adesina was the Nigerian Agriculture Minister from 2010 to 2015.[12] Adesina was named Forbes African Man of the Year, for his reform of Nigerian agriculture. He introduced more transparency into the fertiliser supply chain.[13] He also said that he would give away mobile phones to farmers, but this proved too difficult. One of the reasons was lack of a mobile network in country areas.[14]
In 2010, United Nations Secretary General, Ban Ki-moon, appointed him as one of 17 global leaders, to spearhead the Millennium Development Goals.[4]
On 28 May 2015, Adesina was elected the presumptive President of the African Development Bank. He began his tenure of the office on 1 September 2015.[15]
In September 2016, Adesina was appointed by United Nations Secretary-General, Ban Ki-moon, to serve as member of the Lead Group of the Scaling Up Nutrition Movement.[16] In 2017, he was awarded 2017 World Food Prize.[17]
On 27 August 2020, Adesina was re-elected as President of the Africa Development Bank for a second term of five years.[18]
Ìgbésí ayé rẹ
àtúnṣeNígbà tí ó wà ní Purdue University, Adesina àti aya rẹ̀, pẹ̀lú àwọn tọkọtaya mìíràn, ẹgbẹ́ ọmọlẹ́yìn Jésù tí wọ́n pè ní African Student Fellowship.[7] Òun àti aya rẹ̀, Grace, ní ọmọ mẹ́ta, Rotimi, Emmanuel àti Segun.[19]
Recognition
àtúnṣe- A rí Adesina gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára ẹgbẹ̀rún àwọn tó gbajúmọ̀ jùlọ ní Áfíríkà nínú ìwé ìròyìn New African ní 2
- 2015.[20]
- Ní 2013, a pé é ní Forbes Africa ènìyàn tí ọdún náa .[14]
- Ní 2018, wọ́n fun ni àmì ẹ̀yẹ Honorary Doctor láti Afe Babalola University.[21]
- Ní 2019, a tún pé é ní Forbes Africa ènìyàn tí ọdún náa.[22]
- Ní January 28, 2020, wọ́n fun ní àmì ẹ̀yẹ Honorary Doctor tí ìmò sayensi láti Federal University Of Agriculture, Abeokuta, Nàìjíríà. [23]
- May 14, 2022, he was awarded Honorary Doctor by Addis Ababa University, Ethiopia, for his contributions to the field of economics.[24]
Honours
àtúnṣe- 2019 : Grand Officer of the National Order of Merit of Tunisia.[25]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ The President's biography, African Development Bank
- ↑ "Interview: Akinwumi Adesina, Minister of Agriculture, Nigeria". This is Africa. 30 July 2013. http://www.thisisafricaonline.com/Analysis/Interview-Akinwumi-Adesina-Minister-of-Agriculture-Nigeria?ct=true. Retrieved 19 September 2014.
- ↑ "Transformation agenda, a surgical operation on Nigeria - Agric Minister". LinkedIn. 19 June 2012.
- ↑ 4.0 4.1 "Biography". African Development Bank - Building today, a better Africa tomorrow (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-04-04. Retrieved 2020-05-28.
- ↑ "Akinwumi Adesina: from farmer's son to Africa bank chief". African Spotlight. 28 May 2015. Archived from the original on 2016-09-22. Retrieved June 1, 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Nigerian Minister, Adesina, Elected President Of African Development Bank". Sahara Reporters. 2015-05-28. Retrieved 2022-03-08.
- ↑ 7.0 7.1 Delmar Broersma (2017). God's Surprises Along the Journey. pp. 89–93. ASIN B077DZ8JTP.
- ↑ "Dr. Akinwumi A. Adesina". High-Level Meeting on Drought National Policy. March 2013. Archived from the original on 2013-08-07. Retrieved 19 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "AfDB's Akinwumi Adesina named 2017 World Food Prize Laureate". CNBC Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-06-26. Archived from the original on 2020-08-03. Retrieved 2020-05-28. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "AfDB's Akinwumi Adesina named 2017 World Food Prize Laureate". CNBC Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-06-26. Archived from the original on 2020-08-03. Retrieved 2020-05-28. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "The Travails of Akinwumi Adesina".
- ↑ NIRA gets 3 life Patrons, IT Realms, Retrieved 23 January 2016
- ↑ "Nigerian is 'African of the year'" (in en-GB). BBC News. 2013-12-03. https://www.bbc.com/news/world-africa-25199787.
- ↑ 14.0 14.1 "Nigeria's Akinwumi Adesina named Forbes African of the Year". BBC. December 3, 2013. https://www.bbc.com/news/world-africa-25199787. Retrieved 23 January 2016.
- ↑ Dogbevi, Emmanuel K. (1 September 2015). "Africa can no longer manage poverty, we must eliminate it – Adesina". Ghana Business News. Retrieved 1 September 2015.
- ↑ Secretary-General Appoints 29 Global Leaders to Spearhead Fight against Malnutrition United Nations, press release of 21 September 2016.
- ↑ "AfDB President Akinwumi Adesina wins $250,000 World Food Prize". africanews. 27 June 2017.
- ↑ "Akinwunmi Adesina re-elected as AFDB president". Sellbeta. 27 August 2020. Archived from the original on 25 January 2021. Retrieved 27 August 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Profile:Akinwuni Adesina, Ogala Wordpress
- ↑ "Nigerians dominate New Africa's 100 Most Influential Africans of 2015". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-11-24. Retrieved 2021-01-06.
- ↑ "Afe Babalola University Confers Honorary Doctorate Degree on African Development Bank President Akinwumi Adesina". African Development Bank - Building today, a better Africa tomorrow (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-02-08. Retrieved 2020-02-03.
- ↑ "African Of The Year". Forbes Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-18. Retrieved 2021-08-31.
- ↑ FUNAAB (2020-01-30). "27th Convocation Begins". FUNAAB (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-01-31. Retrieved 2020-02-03. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "AfDB President, Akinwumi Adesina, Receives Honorary Degree In Ethiopia". METRO DAILY Ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-05-16. Retrieved 2022-05-16.
- ↑ "Akinwumi A. Adesina à Caïd Essebsi: La BAD disposée à soutenir la Tunisie dans divers domaines".