Aláàfin Abíọ́dùn

Aláàfin ìlú Ọ̀yọ́ nígbà kan rí

Abíọ́dún (ṣàkóso ìjọba láàárin 1770 sí 1789) jẹ́ aláàfin sẹ́ńtúrì kejìdínlógún, tàbí ọba ti àwọn èèyàn ní nǹkan tí ó wá di Nàìjíríà.[1][2]

Abiodun
Reign 1770-1789
Predecessor Majeogbe
Successor Awole Arogangan
Born Oyo Empire
Died Oyo Empire

Ìlú Ọ̀yọ́

àtúnṣe

Bó ti ń gorí oyè lẹ́yìn ìgbà díẹ̀ tí Ọ̀yọ́ borí ìlú Dahomey tó jẹ́ amúlétì wọn, Abíọ́dún bára rẹ̀ nínú ogun abẹ́lé lórí bí wọn yóò ṣe ṣètò ọrọ̀ ìlú.[3][4]

Baṣọ̀run Gáà,

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. David D. Laitin (15 June 1986). Hegemony and Culture: Politics and Change Among the Yoruba. University of Chicago Press, 1986. p. 113. ISBN 9780226467900. https://books.google.com/books?id=dHbrDvGQEbUC&dq=Abiodun+Alaafin+Oyo&pg=PA113. 
  2. "Abiodun". Encyclopædia Britannica. Retrieved September 26, 2015. 
  3. Mark R. Lipschutz (1989). Dictionary of African Historical Biography. University of California Press. p. 2. ISBN 978-0-520-06611-3. https://books.google.com/books?id=QYoPkk04Yp4C. 
  4. Mark R. Lipschutz (1989). Dictionary of African Historical Biography. University of California Press. p. 2. ISBN 978-0-520-06611-3. https://books.google.com/books?id=QYoPkk04Yp4C.