Aláàfin Ìlú Ọ̀yọ́

Ìgbà Yí Lolá.
(Àtúnjúwe láti Alaafin of Oyo)

Aláàfin tàbí Aláàfin ìlú Ọ̀yọ́ jẹ́ orúkọ oyè ọba ìlú Ọ̀yọ́. Agbègbè tí wọ́n ti ń ṣèjọba wà ní apá ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Áfríkà. Láti ọdún 1900 tí wọ́n ti apá ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bíi kókóìlú, gbogbo olórí ìlú náà ti jẹ́ yálà oyinbo aláwọ̀ funfun tàbí ọmọ dúdú tó gbajúmọ̀ gan-an.

Nínú èdè Yorùbá, wúnrẹ̀n "ọba" túnmọ̀ sí olórí ìlú. Gbogbo ìlú tó wà ní ilẹ̀ Yorùbá ló ní orúkọ tí wọ́n ń pe ọba wọn. Ní ìlú Ọ̀yọ́, Aláàfin ni orúkọ tí wọ́n ń pe ọba wọn, èyí tí a lè túnmọ̀ sí "ẹni tó ni àfin".[1]

Orúkọ àwọn Aláàfin tó ti jẹ sẹ́yìn àtúnṣe

Tenure Incumbent Notes
c.1300 Foundation of Oyo Empire
c.1300 Oranyan, Alaafin grandson or some say son, of Oduduwa, founder of the second Ife dynasty and ancestor to most kings of Yorubaland.
c. to c. Ajaka, Alaafin Succeeded his father, Oranyan. He was said to be a peaceful and calm king, unlike his father, and brother, and his peacefulness caused his more angry and powerful brother to take over and overthrow him.
c. to c. Shango, Alaafin Another son of Oranyan, he was appointed by the Oyo Mesi after dethroning his brother, Ajaka, he reigned for 7 years, after which he became regarded as an orisha having been combined with Jakuta, an earlier orisha in Yoruba mythology
c. to c. Ajaka (restored), Alaafin Ajaka returned to the throne after the death of his brother.
c. to c. Aganjusola, Alaafin Son of Ajaka who succeeded his father. He was said to have tamed many wild animals, and he reigned for an incredibly long time. He is synonymous with the Yoruba deity of the same name
c.1400 to c.1457 Kori, Alaafin Succeeded his father, Aganju, who died while he was still a child. The early period of his reign was overseen by his mother, Iyayun as regent. He waged a war with town of Ede. Under Alaafin Kori, the city of Oyo Ile expanded to include the region referred to as metropolitan Oyo. He is also regarded to have reigned over 50 years making him the longest reigning Alaafin.
c. 1457 to c. 1500 Oluaso, Alaafin Succeeded his father, Kori. He was said to be handsome and had up to 1,460 children by his hundreds of wives. O ni ki ogbogbo Oluaso, O le je iya Oluaso - is a saying often interpreted as he living a long but challenging life
c. 1500 to c. 1537 Onigbogi, Alaafin Nupe expanded to occupy Oyo's capital, driving the Alaafin away from his capital in 1535. He fled to take refuge with the Borgu
???? to ???? Ofiran, Alaafin Crowned a King in exile after a period of regency by his Mother, Oba Adasobo. He is sometimes considered the 10th Alaafin when the regency of Iyayun and Adasobo are counted. He retook some of Oyo's original territory from the Nupe.
???? to ???? Eguguojo, Alaafin Created Igboho as new capital.
1555 to 1575 Orompoto, Alaafin Sister of Eguguojo, and first break of the Father-Son succession pattern since Aganju succeeded Ajaka. Drove the Nupe away from Oyo in 1555.
 ???? to ???? Ajiboyede, Alaafin
c.??? to ???? Abipa, Alaafin Born 20 years after the Fall of Oyo-Ile. Rebuilt Oyo-ile back as capital after 80 years in 1615
???? to ???? Obalokun, Alaafin
???? to ???? Oluodo, Alaafin
???? to ???? Ajagbo, Alaafin First Alaafin to wear the Sesefun crown. He also created the Aare Ona Kankanfo title
???? to ???? Odarawu, Alaafin
???? to ???? Kanran, Alaafin He was killed during a mutiny of his army
???? to ???? Jayin, Alaafin
???? to ???? Ayibi, Alaafin
???? to ???? Osiyago, Alaafin Assassinated by a personal enemy
c. 1724 to 1730 Ojigi, Alaafin He conquered the Dahomey Kingdom
c. ??? to ??? Gberu, Alaafin
??? Amuniwaiye, Alaafin Assassinated by a personal enemy
??? to 1754 Onisile, Alaafin
July 1754 Labisi, Alaafin He never formally ruled, and was instead on the 17th day of his installation ceremony before being compelled to commit suicide by Bashorun Gaa
July 1754 to October 1754 Awonbioju, Alaafin He ruled for about 130 days, before being compelled to suicide by Bashorun Gaa
1754 to c.1768 Agboluaje, Alaafin He was forced to commit suicide by Bashorun Gaa after refusing to declare war against the town of Ifonyin
c.1768 to c.1774 Majeogbe, Alaafin Brother of Agboluaje
c. 1774 to April 1789 Abiodun, Alaafin Defeated Bashorun Gaa with the support of Oyabi, the Aare Ona Kakanfo. The Egba got their independence during his reign
1789 to 1796 Awole Arogangan, Alaafin Son of Agboluaje, he installed Afonja of Ilorin as Aare Ona Kakanfo, a distant relative to the Oyo royal family. He was overthrown by Afonja and his army where he committed suicide by poison.
1796 to 1797 Adebo, Alaafin He ruled for about 130 days, he died likely by suicide or murder
1797 Makua, Alaafin He ruled for only two months
1797 to 1802 vacant, vacant The Bashorun Ashamu served as regent during this period
1802 to 1830 Majotu, Alaafin Is said to have been quite old when he ascended the throne. During his reign Ilorin seceded from Oyo and in 1823 Dahomey under Ghezo got their independence
1830 to 1833 Amodo, Alaafin
1833 to 1835 Oluewu, Alaafin the Fall of Oyo empire after the Eleduwe war.
1837 to 1859 Atiba Atobatele (at new capital), Alaafin Son of Alaafin Abiodun. He maintained influence over cities like Ijaye and Ibadan by given titles to their leaders while continuing to call himself 'emperor' and maintained the claim to rule over Yoruba speaking areas even outside his influence.
1859 to 1875 Olujide Adelu Agunloye, Alaafin Eldest son of Atiba. He was chosen by Atiba to ascend the throne after him.
1876 to 12 November 1894 Adeyemi I Alowolodu, Alaafin A son of Atiba. He was the last independent Alaafin of Oyo. Signed Treaty with the British on July 3, 1888. On November 12, 1894, the town of New Oyo was bombarded and brought forcibly under British colonial rule.
12 November 1894 to 1905 Adeyemi I Alowolodu (as British Vassal), Oba
1905 to 1911 Lamidi Amubieya Agogoja (as British Vassal), Oba Eldest son of Alaafin Adelu
1911 to 1944 Siyanbola Onikepe Oladigbolu I (as British Vassal), Oba Son of Agogoja
1944 to 1945 Regent (as British Vassal), Oba
1945 to 1955 Adeyemi II Adeniran (as British Vassal), Oba Son of Adeyemi I
1955 to 1956 Regent (as British Vassal), Oba
1956 to 1960 Bello Gbadegesin Oladigbolu II (as British Vassal), Oba Son of Alaafin Oladigbolu I
1960 to 1968 Bello Gbadegesin Oladigbolu II (as Nigerian Traditional Monarch), Oba
19 November 1970 to 22 April 2022 Lamidi Olayiwola Adeyemi III (as Nigerian Traditional Monarch), Oba
 

Tún wo àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Radio, Ajisebi Oyo (2022-11-10). "Ọ̀yọ́ Aláàfin Anthem Lyrics – Ajisebi Oyo Radio & TV". Ajisebi Oyo Radio & TV – Oyo o ni se bi baba eni kookan. Archived from the original on 2023-06-12. Retrieved 2023-06-12.