Al-Wafa bi Asma al-Nisa

Al-Wafa bi Asma al-Nisa ( Arabic </link> ni ìwé òdodo tí ó kún fún àwọn orúkọ Obìnrin) ó jẹ́ ìwé tí ó ní ìwọn ẹ̀tà-lẹ́-lógójì tí ó dá lóri ìgbésí ayé àwọn Lárúbáwá tí wọ́n jẹ́ obìnrin tí wọ́n jẹ́ olùkópa nínú àlàyé tí àwọn Àdíìsì tàbí kó ipa ribiribi nínu ìfiléde.

Al-Wafa bi Asma al-Nisa
Fáìlì:Cover of Al-Wafa bi Asma al-Nisa.jpg
Arabic cover
Olùkọ̀wéAkram Nadwi
CountryUnited Kingdom
LanguageArabic
SubjectHadith studies
GenreBiography
PublisherDar al-Minhaj
Publication date
2021
ISBNÀdàkọ:ISBNT
OCLC1252541014
920.71
Websitealsalam.ac.uk
An introductory note in English for the book Al-Muhaddithat, released in 2007

Afoyemọ

àtúnṣe

Iṣẹ́ náà jẹ́ àwọn ìpele ìwọ̀n mẹ́tà-lé-lógójì. Iwọn akọkọ ṣe àfihàn àwọn àlàyé tí àwọn Àdíìsì tí wọ́n dárí sọ àwọn obìnrin tí wọ́n jẹ́ olùkópa, nígbà tí ìwọn ẹlẹ́ẹ̀kejì ṣé àgbéyẹ̀wò àwọn obìnrin ilé ẹ Ànábì. Àwọn ìpele tí ó tẹ̀lé e ṣe àlàyé àwọn ẹlégbè obìnrin (3–10), Tabi’un (11–13) àti àwọn òpìtàn-onímọ̀ (14–42) ní àsọtẹ́lẹ̀ ní bíi àwọn ọgọ́rùn-ún ọdún. Ìwọn 43 yí padà sí orí àwọn òpìtàn-onímọ̀ òde òní, pẹ̀lú díẹ̀ nínú àwọn tí wọ́n tún ṣiṣẹ́ lọ́wọ́ . [1] Ìwé náà gbé ìtàn àkọ́lé òtító tàbí a bójú-ayé-mú gorí í ìtúpalẹ̀, àwọn ìgbìyànjú láti mú ìwòye àgbáyé nípa fífi Àdíìsì àwọn obìnrin tí wọ́n jẹ́ òpìtàn-onímọ̀ hadith obinrin tí wọ́n wà ní ìkọjá a Àárín-in Ìlà-Oòrùn. Àwọn títẹ síi ìtàn-ayé yàtọ̀ ni ìjìnlẹ̀, pẹ̀lú àkọyawọ́ tí ó léni ojú ìwé igba ti o tẹpẹlẹ mọ́ àtúnṣe sí iṣẹ́ àwọn yòókù, ní kúkúrú nípa àwọn òpìtàn-onímọ̀ ọkùnrin. Wọ́n ṣe àwọn àkójọpọ̀ yìí látara àwọn ìpamọ́ bíi ìwé ìforúkọsílẹ̀ ní yàrá ìkẹ́kọ̀ọ́ àti ijazahs, ní èyí tí ó ṣe àfihàn bí àwọn obìnrin ṣe gbé àṣẹ lé àwọn ọkùnrin lọ́wọ́ láti má a kọ́ni. Ó tún lo ìtọ́ka láti ọ̀dọ 'ulema tí ó ṣe wí pé o

abẹ́lé

àtúnṣe

Ní ọdún-un 1989, Akram Nadwi kó ipa ti Ẹlẹgbẹ́ Ìwádìí kan ní Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Oxford ti Oxford Centre fún Islamic Studies, ní èsì sí ìdá ìbéèrè láti ọ̀dọ Abul Hasan Ali Hasani Nadwi. Nígbà ìṣàkóso rẹ̀, ó ṣe àbápàdé àwọn àkọ́lé kan nínú ìwé ìròyìn "Time'' tí wọ́n ṣe àtẹ̀jáde wí pé wọ́n ń ṣe ìdènà fún obìnrin nínú ẹ̀kọ́ ọ wọn, wí pé obìnrin ò ní ipa tí wọ́n ń kó nínú ẹ̀kọ́ àti ìmọ̀ tí ó dá lóri iṣẹ́ ìwádìí nínú Islam.

Gbígbàwọlé

àtúnṣe

Dhaka Post ṣe àfihàn pàtàkì ti iṣẹ́ yìí ní sísọ ìtàn ọgbọn-ọ-gbọ́n Islam ti ọ̀rúndún 21st, tí ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi itọkasí àti ìwífún tí ó lágbára lòdì sí àwọn àìṣe-déédé Islam, pàápàá ní sísọ àwọn ẹ̀sùn èké tí ó ní ìbátan sí ìlọsíwájú àti ẹ̀kọ́ àwọn obìnrin. [2] Majalla yin iṣẹ́ yìí gẹ́gẹ́ bí ìwé ìmọ̀ àgbọ́n-ọ̀n-gbẹn tí wọ́n fi sọrí àwọn obìnrin tí wọ́n lààmì-laaka tí wọ́n sì tún jẹ́ onísọ̀rọ̀ Àdíìsì . [3]

Àwọn ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. Empty citation (help) 
  2. Minhaj Uddin, Muhammad (14 January 2021). "Exploring the Contributions of Muslim Women Scholars: A 43-Volume Compilation" (in bn). Dhaka Post. Archived on 27 July 2021. Error: If you specify |archivedate=, you must also specify |archiveurl=. https://www.dhakapost.com/amp/religion/5338. 
  3. Al-rashid, Abdullah (17 October 2023). "The 'unknown' Arab and Muslim women scholars, who taught some of history's most esteemed men". The Majalla. Archived on 20 November 2023. Error: If you specify |archivedate=, you must also specify |archiveurl=. https://en.majalla.com/node/300871/culture-social-affairs/unknown-arab-and-muslim-women-scholars-who-taught-some-historys.