Alain Juppé
Alain Marie Juppé (ìpè Faransé: [alɛ̃ ʒype]; bíi ní Ojọ́ karùndínlógún Oṣù Kẹjọ Ọdún 1945) jẹ́ alákóso àgbà orílẹ̀ èdè France tẹ́lẹ̀ lati ọdún 1995 sí 1997 lábẹ́ ìjọba ààrẹ Jacques Chirac, tí kò sì gbajúmọ̀. Ófi ìjọba sílẹ̀ lẹ́yin ìdìbò ọdún 1997.[1][2][3]
Alain Juppé | |
---|---|
164th Prime Minister of France 15th Prime Minister of Fifth Republic | |
In office 18 May 1995 – 3 June 1997 | |
Ààrẹ | Jacques Chirac |
Asíwájú | Édouard Balladur |
Arọ́pò | Lionel Jospin |
Minister of State for Ecology and Sustainable Development | |
In office 18 May 2007 – 18 June 2007 | |
Alákóso Àgbà | François Fillon |
Asíwájú | Nelly Olin |
Arọ́pò | Jean-Louis Borloo |
Minister of Foreign Affairs | |
In office 29 March 1993 – 18 May 1995 | |
Alákóso Àgbà | Édouard Balladur |
Asíwájú | Roland Dumas |
Arọ́pò | Hervé de Charette |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Kẹjọ 1945 Mont-de-Marsan, France |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | (1) RPR (2) UMP |
Occupation | Civil Servant |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Decision from the Minister of Economy, finances and industry of 13 November 2002, admitting Alain Juppé into retirement.
- ↑ "Young Leaders". French-American Foundation. Retrieved 2015-10-26.
- ↑ Le Rwanda menace de poursuivre Balladur, Juppé, Védrine et Villepin – L'EXPRESS. Lexpress.fr. Retrieved on 9 April 2011.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |