Alash'le Grace Abimiku jẹ́ adarí ààjọ International Research Centre of Excellence ni Institute of Human Virology Nigeria àti ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmò vírusì ní Yunifásítì Maryland School of Medicine tí ó ní ìfẹ́ sí bí a ti le yàgò fún àrùn HIV àti bí a ṣe le tọjú àwọn tí ó ní àrùn HIV.[1]

Alash'le Abimiku
ÌbíAlash'le Grace Abimku
Nigeria
Ilé-ẹ̀kọ́University of Maryland School of Medicine
Institute of Human Virology Nigeria
Ibi ẹ̀kọ́Ahmadu Bello University
London School of Hygiene & Tropical Medicine (PhD)
Ó gbajúmọ̀ fúnRetrovirology

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Online, The Eagle (2017-08-10). "How HIV positive mothers can breastfeed exclusively —Director |". The Eagle Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-11-07.