Alemitu Tariku
Alemitu Tariku Olana ti a bini ọjọ kèji dinlọgbọn óṣu september ni ọdun 2000 jẹ elere to man sare fun idije ti ilẹ Ethiópíà[1][2][3][4].
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Alemitu Tariku Olana |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Ethiópíàn |
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kẹ̀sán 2000 |
Sport | |
Orílẹ̀-èdè | Ethiópíà |
Erẹ́ìdárayá | Athletics |
Event(s) | 3000m, 5000m |
Iṣẹ ati Ipa Àràbinrin naa
àtúnṣeAlemitu kopa ninu idije agbaye ti ilu Aarhus ni ọdun 2019 nibi ti arabinrin naa gba ami ẹyẹ ti silver ninu U20 ni iṣẹju 20:50 lẹyin naa logba ami ẹyẹ ti gold pẹlu team rẹ to wa lati ilu Ethiopia[5][6][7].
Arabinrin naa dije ninu ere idije junior ti ilẹ afirica ni ilu abidjan nibi toti yege ninu 3000 meter dash ni iṣẹju 9:33:53[8][9].
Ami Ẹyẹ ati Idanilọla
àtúnṣeỌdun | Competition | Position | Event | Time | Wind (m/s) | Venue | Notes |
---|---|---|---|---|---|---|---|
Ọdun 2019 | World Cross Country Championships | Ipo Keji | Under 20 Race | 20:50 | Aarhus, Denmark | ||
Ọdun 2019 | All African Games | Ipo Kẹta | 5000 Metres Race | 15:37:15 | Complexe Sportif Prince Moulay Abdellah, Rabat Morocco | ||
Ọdun 2019 | African U20 Championships | Ipó akọkọ | 3000 Metres Race | 9:33:53 | Abidjan Cote d'Ivoire |
Àwọn Itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://www.watchathletics.com/article/11604/seven-runners-runs-madrid-half-marathon-in-less-than-1-hour
- ↑ https://www.the-sports.org/alemitu-tariku-athletics-spf585787.html
- ↑ https://worldathletics.org/athletes/ethiopia/alemitu-tariku-14848725
- ↑ "BEST sports DBďťż - Profile - Alemitu TARIKU - Ethiopia - Athletics". Bestsports.com.br. Retrieved 2023-03-04.
- ↑ https://www.fashionghana.com/site/upcoming-african-athletes-the-young-guns-to-look-out-for/
- ↑ https://olympics.com/en/news/hellen-obiri-world-cross-country-only-medal-missed
- ↑ https://www.worldathletics.org/results/world-athletics-cross-country-championships/2019/iaaf-world-cross-country-championships-aarhus-7125363/women/u20-race/final/split
- ↑ https://www.athleticspodium.com/athlete/27197/alemitu-tariku
- ↑ Posted by: admin (2019-04-18). "African u20 championships, Abidjan (Ivory Coast) 16-20/04/2019". Africathle. Retrieved 2023-03-04.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]