Alex Ekwueme

Olóṣèlú
(Àtúnjúwe láti Alex Ifeanyichukwu Ekwueme)

Alex Ifeanyichukwu Ekwueme (ojoibi October 21, 1932) je oloselu ati Igbakeji Aare ile Naijiria si Aare Shehu Shagari ni Igba Oselu Keji lati 1979 de 1983.

Igbákejì Ààre Alex Ifeanyichukwu Ekwueme láti orílè-èdè Nàìjíríà ni a kí káàbò nígbàtí ó dé fún àbèwò sí Améríkà.
Alex Ekwueme