Shehu Shagari
Olóṣèlú
Shehu Usman Aliyu Shagari (bíi ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọn Oṣù Keji Ọdún 1925-2018) jẹ̣́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà lati ọjọ́ kínni oṣù Kẹwá ọdún 1979 títí di ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù Kejìlá ọdún 1983 nígbàtí àwọn ológun gba ìjọba.
Shehu Shagari | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà 6k | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
In office October 1, 1979 – December 31, 1983 | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Vice President | Alex Ekwueme | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Asíwájú | Olusegun Obasanjo (Military) | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Arọ́pò | Muhammadu Buhari (Military) | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
| |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Àwọn àlàyé onítòhún | |||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Ọjọ́ìbí | Shagari, Northern Region, British Nigeria (now Shagari, Nigeria) | Oṣù Kejì 25, 1925||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Aláìsí | December 28, 2018 Abuja, Nigeria | (ọmọ ọdún 93)||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | National Party of Nigeria | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Àwọn ọmọ | Muhammad Bala Shagari Aminu Shehu Shagari Abdulrahman shehu shagari | ||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||||
Relatives | Bello Bala Shagari (Grandson) |
Ìgbé yawo
àtúnṣeShehu Shagari Fẹ́ ìyàwó Mẹta:Amina, Aisha, àti Hadiza. Shagari bí ọmọ púpò lára wọn ni:Muhammad Bala Shagari àti Aminu Shehu Shagari. Ní Ọdún 2001 Ọjọ́ kẹfà dín ni ọgbọ́n ,Ìyàwó rè Aisha Shagari, kú ní ilé ìwòsàn kàn ní Lọ dòní íLẹ́yìn sì kí nesi kékeré gan.Àìsàn Covidi ni ó pá Ìyàwó Shehu Shagari Ní ọdún 2021.
Ìgbà tí òkú
àtúnṣeNi ó jọ méjì dín lọ gbọn oṣù Kejìlá ni ọdún 2018 ni ọwọ irole. Ìṣàn rán pé ní o pá Ogbeni Shehu Shagari ni ìwòsàn àpapọ̀ kàn ní Abuja.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "The old Bureaucracy is coming back – Eric Teniola". Nigerian Insight. Archived from the original on 19 June 2015. Retrieved 19 June 2015.
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Shehu Shagari |