Nọ́mbà áljẹ́brà
(Àtúnjúwe láti Algebraic number)
Ninu mathematiiki, nomba aljebra je nomba tosoro kan to je wewe polynomial tikoje-odo ni oniyekiye eyo kan pelu oniipin (tabi lonibamu, odidi) afisodipupo. Awon nomba bi ti won ki se ti aljebra ni won so pe won je transcendental; Bi gbogbo won nomba gidi ni won je transcendental.
Àwọn àpẹrẹ
àtúnṣe- Àwọn nọ́mbà gidi, tí wọ́n jẹ́ gbígbékàlẹ̀ bíi ìpín nọ́mbà odidi méjì a àti b, tí b kò dọ́gba mọ́ òdo, nitelorun ìtumọ̀ ọkè nítorí ni wẹ́wẹ́ .[1]
- Àwọn nọ́mbà aláìníìpín kan jẹ́ ti áljẹbrà, àwọn kan kò jẹ́ bẹ́ẹ̀:
- Àwọn nọ́mbà àti jẹ́ ti áljẹ́brà nítorípé àwọn ni wẹ́wẹ́ àwọn polynomials àti , nitelentele.
- Ipin oniwura je ti aljebra nitoripe o je wewe kan polynomial .
- Awon nomba ati ko je nomba aljebra (e wo Lindemann–Weierstrass theorem);[2] nitori eyi won je transcendental.
- Awon nomba kiko (those that, starting with a unit, can be constructed with straightedge and compass, e.g. the square root of 2) je ti aljebra.
- Awon quadratic surd (awon wewe quadratic polynomial pelu awon odidi afisodipupo , , ati ) je nomba onialjebra. Ti quadratic polynomial ba je monic nigbana awon wewe je quadratic integer.
- Awon nomba odidi Gauss: awon nomba tosoro nibi ti ati ati je odidi na tun je quadratic integers.
Awon ini nomba aljebra
àtúnṣe- Akojopo awon nomba aljebra je siseeka (enumerable).[3]
- Bi be, akojopo awon nomba aljebra ni iwon Lebesgue odo (gege bi akojopoabe fun awon nomba tosoro)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Some of the following examples come from Hardy and Wright 1972:159-160 and pp. 178-179
- ↑ Also Liouville's theorem can be used to "produce as many examples of transcendentals numbers as we please," cf Hardy and Wright p. 161ff
- ↑ Hardy and Wright 1972:160