Alhaji Rájí Àlàbí Owónikókó
Alhaji Muhammed Rájí Àlàbí Owónikókó Jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà,olórin Àpàlà. Wọ́n bí Rájí ní ìlú Òró ní ijoba ibile Irepodun ìpínlẹ̀ Kwárà.[1] [2] [3]
Àwọn Ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "Today’s Musicians Are Lazy". PM NEWS Nigeria. 2012.
- ↑ "Alhaji raji by Owonikoko & His Apala Group, LP with ketu-records". CD and LP. 2016-08-29. Retrieved 2018-10-26.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "• Alhaji Raji • Mushin • Lagos • mablesourcee.com". www.tuugo.com.ng. 1937-05-18. Archived from the original on 2023-10-04. Retrieved 2018-10-26.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |