Alkaki jẹ́ oúnjẹ àwọn ẹ̀yà Hausa èyí tí a máa ń ṣe láti ara wíìtì, ṣúgà tàbí oyin, ó jẹ́ èyí tí a sáábà máa ń rí nínú ilé àwọn olówò àti ọlọ́lá tí wọ́n jẹ́ Hausa àti ilé àwọn ìyàwó tuntun.[1][2] Alkaki jẹ́ ìpanu tí a le tọ ipasẹ̀ rẹ̀ lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn ará àríwá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí a mọ̀ fún adùn rẹ̀. Adùn rẹ̀ máa ń wáyé látàrí tí tì í bọ inú oyin tàbí ṣúgà èyí tí á mú kí adùn rẹ̀ ó dùn. Wọ́n mọ Alkaki káàkiri ojú pópónà àti ní àwọn òde.[3]

Alkaki
TypeDoughnut
CourseSnack
Place of originNigeria
Region or stateNorthern Nigeria
Main ingredientsWheat, yeast, sugar, salt, Honey, water, vegetable oil
Other informationit's also consumed in Niger, Mali, Cameroun and some other west African countries.
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Wò pẹ̀lú

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "How to Make Alkaki Hausa Snack - Northpad Nigeria". northpad.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-09-16. Retrieved 2023-09-27. 
  2. "Alkaki Recipe by Augie's Confectionery". Cookpad (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-09-23. Retrieved 2023-09-27. 
  3. Goodness, Spicy & Delicious. "Spicy & Delicious Goodness". Spicy & Delicious Goodness (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-27. 

Àdàkọ:Dessert-stub