Allah
Allah (Lárúbáwá: الله Allāh, IPA: [ʔalˤːɑːh] ( listen)) ni oro fun Olorun ni ede Arabiki.[1] Botilejepe a mo nibo miran bi oro awon musulumu fun Olorun, oro yi gbogbo na ni awon Arabu yioku onigbagbo Abrahamu unlo fun "Olorun", awon bi Mizrahi Jews, Baha'is ati Eastern Orthodox Christians.[1][2][3] Oro yi na tun ni awon keferi ara Meka na tu lo fun olorun-eleda, o seese ko je orisa igba na ni Arabia akosiwaju-Imale.[4][5]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Allah." Encyclopædia Britannica. 2007. Encyclopædia Britannica
- ↑ Encyclopedia of the Modern Middle East and North Africa, Allah
- ↑ Columbia Encyclopedia, Allah
- ↑ L. Gardet, "Allah", Encyclopedia of Islam
- ↑ Smith, Peter (2000). "prayer". A concise encyclopedia of the Bahá'í Faith. Oxford: Oneworld Publications. pp. 274–275. ISBN 1-85168-184-1.