Aloïs Dansou (ojoibi 1982) [1] je olowe Olimpiiki lati ilu Benin . [2] O we fun orilẹ-ede Benin ni amon ìdíje wonyi:

  • Olimpiiki: 2004, 2008
  • World Championships: 2003, 2007
  • Idije Odo Afirika: 2004

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. Dansou's result page from the FFN website; retrieved 2013-06-05.
  2. Dansou's entry from sports-reference.com. Retrieved 2013-06-05.