Aloysius Akpan Etok
Olóṣèlú
Aloysius Akpan Etok jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àríwá-ìwọ oòrùn Ìpínlẹ̀ Ibom State ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2007 sí Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2]
Aloysius Akpan Etok | |
---|---|
aṣojú àríwá-ìwọ oòrùn Ìpínlẹ̀ Ibom State ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà | |
In office 2007–2015 | |
Constituency | Àríwá-ìwọ oòrùn Ìpínlẹ̀ Ibom State |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Kejì 1958 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Profession | olóṣèlú àti olùkànsí |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Senator Etok's Biography". Senator Aloysius Etok. Retrieved 2009-09-22.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "A/Ibom, Rivers in Fresh Battle over NDDC’s Top Position". BusinessWorld. 2 July 2009. Archived from the original on 2013-01-19. Retrieved 2009-09-22.