Aluminium ní Áfríkà

Àwọn Aluminium ní Áfríkà búyọ láti ara àpáta bauxite, wọ́n sì ń rí wọn ní àwọn orílẹ̀-èdè bi Guinea, Mozambique àti Ghana. Guinea ni órílẹ̀ èdè tí ó ń ṣe aluminium jáde jù ní Áfríkà, òun sì tún lọ ṣàgbéjáde òkúta bauxite jùlọ.

Ọ̀pọ̀lopọ̀ orílẹ̀ èdè ni ó wà nínú títà àti rírà aluminium ní Áfríkà. Àwọn bi:

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 http://railwaysafrica.com/index.php?option=com_content&task=view&id=3381&Itemid=35
  2. "Mozambique: Mozal Suffers From South African Energy Crisis". Agencia de Informacao de Mocambique (Maputo). 2008-06-10. http://allafrica.com/stories/200806101031.html.