Guinea (pípè /ˈɡɪni/, lonibise bi Orile-ede Olominira ile Guinea Faranse: République de Guinée), je orile-ede kan ni Iwoorun Afrika. Mimo teletele bi Guinea Faranse (Guinée française), nigba miran loni bi Guinea-Conakry lati seyato re si Guinea-Bissau to wa legbe re.[3] Conakry ni oluilu, ibujoko ijoba olomoorile-ede ati ilu ttobijulo.

Republic of Guinea
République de Guinée
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto"Travail, Justice, Solidarité"  (French)
"Work, Justice, Solidarity"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèLiberté  (French)
"Freedom"

Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Conakry
9°31′N 13°42′W / 9.517°N 13.7°W / 9.517; -13.7
Èdè àlòṣiṣẹ́ French
Vernacular languages Pular, Mandinka and Susu
Orúkọ aráàlú Ará Guinea
Ìjọba Military junta
 -  Aare Adipo Sékouba Konaté
 -  Alakoso Agba Jean-Marie Doré
 -  Aare adiboyan Alpha Condé
Ilominira
 -  from France¹ October 2, 1958 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 245,857 km2 (78th)
94,926 sq mi 
 -  Omi (%) negligible
Alábùgbé
 -  Ìdíye July 2009 10,057,975[1] (81st)
 -  1996 census 7,156,406 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 40.9/km2 
106.1/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2009
 -  Iye lápapọ̀ $10.516 billion[2] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $991[2] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2009
 -  Àpapọ̀ iye $4.394 billion[2] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $414[2] 
Gini (1994) 40.3 (medium
HDI (2007) 0.435 (low) (170th)
Owóníná Guinean franc (GNF)
Àkókò ilẹ̀àmùrè (UTC+0)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .gn
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 224


ItokasiÀtúnṣe