Amazulu (orin)
Orin ọdún 2016 láti ọwọ́ Amanda Black
Amazulu jẹ́ àwo-orin àkọ́kọ́ ti olórin ilè South Africa, iyẹ̀n Amanda Black, tí ó jáde ní ọjọ́ kìíní oṣù keje ọdún 2016. Orin náà jẹ́ èyí tó mú Amanda Black bọ́ sí gbagede, nítorí ọ̀pọ̀ ènìyàn ló gbọ́ orin náà lásìkò tí ó jáde, ìye ìgbà tí àwọn ènìyàn gbọ́ orin náà jẹ́ ìgbà 53,000.
"Amazulu" | ||||
---|---|---|---|---|
Fáìlì:Amanda Black Amazulu Single.jpg | ||||
Single by Amanda Black | ||||
from the album Amazulu | ||||
Released | Oṣù Keje 1, 2016 | |||
Recorded | 2016 | |||
Genre | ||||
Length | Àdàkọ:Duration | |||
Label | Ambitiouz Entertainment | |||
Songwriter(s) |
| |||
Producer(s) |
| |||
Amanda Black singles chronology | ||||
|
Ìgbóríyìn fún
àtúnṣeWọ́n yan "Amazulu" fún àmì-ẹ̀yẹ Record of the Year ní South African Music Awards ẹlẹ́ẹ̀kẹtàlélógún irú ẹ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ Song of the Year ní Metro FM Awards.
Ọdún | Ayẹyẹ ìgbàmì ẹ̀yẹ | Àpèjúwe àmì-ẹ̀yẹ | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|
2017 | Metro FM Music Awards | Song of the Year | Wọ́n pèé | [1] |
South African Music Awards | Record of the Year | Wọ́n pèé | [2] |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Reporter, Citizen. "Amanda Black gets her first award and Twitter goes crazy". citizen.co.za. Retrieved 15 September 2017.
- ↑ Reporter, Citizen. "Amanda Black talks her music journey & latest project". yomzansi.com. Retrieved 15 September 2017.