Amenze Aighewi

Amenze Aighewi (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kọkànlá ọdún 1991) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan tí o ń gbá ọwọ́ iwájú fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè Naijiria . Ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ti o gbá bọ́ọ̀lù nínú ìdíje FIFA World Cup ti ọdún 2011.[1]

Amenze Aighewi
Personal information
Ọjọ́ ìbí21 Oṣù Kọkànlá 1991 (1991-11-21) (ọmọ ọdún 31)
Playing positionForward
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
Rivers Angels
National team
Nigeria3(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of before the 2011 FIFA Women's World Cup


O gbá bọ́ọ̀lù fún ikọ̀ Rivers Angel ní ìpínlẹ̀ Rivers ní orilẹ̀-èdè Nàìjíríà[2]

Àwọnitọ́ka síÀtúnṣe

  1. "Official squad list 2011 FIFA Women's World Cup". FIFA. 17 June 2011. Archived from the original on |archive-url= requires |archive-date= (help). Retrieved 17 June 2011. 
  2. "Official squad list 2011 FIFA Women's World Cup". FIFA. 17 June 2011. Archived from the original on |archive-url= requires |archive-date= (help). Retrieved 17 June 2011.