Amina J. Mohammed
Amina Jane Mohammed tí a bí ní 27 June 1971 jé olósèlú omo orílè-èdè Nàìjíríà àti orílè-èdè Britain, òun ígbákejì akowe fun Igbimọ gbogboogbo ti orilẹ-ede Agbaye(United Nations) lowolowo,[2] laarin odun 2015 sí 2016, òun ni lo jé minisita Nàìjíríà fun ètó adugbo.[3]
Amina J. Mohammed | |
---|---|
Amina J. Mohammed ní London ní ọdun 2018 | |
Deputy Secretary-General of the United Nations | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 28 February 2017[1] | |
Secretary-General | António Guterres |
Asíwájú | Jan Eliasson |
Minister of Environment | |
In office 11 November 2015 – 15 December 2016 | |
Ààrẹ | Muhammadu Buhari |
Asíwájú | Lawrencia Laraba-Mallam |
Arọ́pò | Ibrahim Usman Jibril |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Amina Jane Mohammed 27 Oṣù Kẹfà 1961 Liverpool, England |
Aráàlú | |
Education | The Buchan School |
Alma mater | Henley Management College |
Ìpìlè àti Èkó rè
àtúnṣeA bí Amina Jane Mohammed ni ojo June 27, 1961 ní ìlú Liverpool, England ní orílè-èdè United Kingdom.[4] Baba rè jé Hausa-Fulani, òsì jé Dókítá alabare àwon eranko, Ìyá rè sì jé Noosi omo orílè-èdè United Kingdom. Amina ni omo àkókó larin omo marun.[5]
Mohammed lo ilé-ìwé Primari ní ìpínlè Kaduna, o sì tèsíwájú ní ilé-ìwé Buchan ní orílè-èdè Isle of Man fún ìwé sekondori rè.[3] O tún tèsíwájú ní Henley Management College ni odún 1989. Léyìn tí o parí èkó rè, bàbá rè so pé kí o padà sí Nàìjíríà.[5]
Isé rè
àtúnṣeLarin 1981 sí 1991, Mohammed sísé pèlú ilé-isé Archon Nigeria, ilé-isé tí oun yaworan ilé. Ni odun 1991, Mohammed dá ilé-isé Afri-projects Consortium kalè, larin odun 1991 sí odun 2001, oun ni adari àti apase ilé-isé náà.[6]
Àwon Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Nigeria's Amina Mohammed swears in as Deputy Secretary-General of the United Nations". New China TV via YouTube. 2017-02-28.
- ↑ "Ms. Amina J. Mohammed of Nigeria - reappointed as Deputy Secretary-General". United Nations Secretary-General. 2022-01-10. Retrieved 2022-08-11.
- ↑ 3.0 3.1 "Amina J. Mohammed". Planetary Security Initiative. 2016-01-18. Retrieved 2022-08-11. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; name "Planetary Security Initiative 2016" defined multiple times with different content - ↑ "Sustainable Development Solutions Network - Amina Mohammed". unsdsn.org. 2016-12-15. Archived from the original on 2016-12-15. Retrieved 2022-08-15. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 5.0 5.1 Seddon, Mark (2017-05-26). "'Why is she here?': the Nigerian herder’s daughter who became UN deputy chief". the Guardian. Retrieved 2022-08-15.
- ↑ "Secretary-General Appoints Amina J. Mohammed of Nigeria as Special Adviser on Post-2015 Development Planning - UN Press". Welcome to the United Nations. 2012-06-07. Retrieved 2022-08-15.