Muhammadu Buhari
Muhammadu Buhari (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ ketàdínlógún, Oṣù Kejìlá Odún 1942) jẹ́ Aàrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà tí wọ́n dìbò yàn sípò ààrẹ fún sáà àkọ́kọ́ ní odún 2015. Òun ló tún wọlé lẹ́ẹ̀kejì gẹ́gẹ́bí Ààrẹ nínú ìdìbò Ààrẹ tí ó wáyé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́dún 2019[5]. Buhari tí fìgbà kan jẹ́ ogágun Méjọ̀ Gẹ́nẹ́rà àti pé ó j̣e olórí orílẹ̀ èdè Nàíjíríà lati 31st Oṣù kejìlá odún 1983 sí Oṣù kẹjó odún 1985, léyìn tí ó fi kúùpù ológun gbàjọba.[6][7]
His Excellency Muhammadu Buhari | |
---|---|
![]() | |
Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà 7k & 15k | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 Oṣù Kàrún 2015 | |
Vice President | Yemi Osinbajo |
Asíwájú | Goodluck Jonathan |
Chair of the Supreme Military Council | |
In office 31 Oṣù Kejìlá 1983 – 27 Oṣù Kẹjọ 1985 | |
Vice President | Tunde Idiagbon (Chief of Staff) |
Asíwájú | Shehu Shagari (President) |
Arọ́pò | Ibrahim Babangida (Chair of the Armed Forces Ruling Council) |
Ijoba Ijoba ti Awọn Ọkọ Ẹrọ | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 11 Kọkànlá Oṣù 2015 | |
Asíwájú | Diezani Allison-Madueke |
Gómínà ìpínlẹ̀ Bọ̀nú | |
In office 3 Oṣù Kejì 1976 – 15 Oṣù Kẹta 1976 | |
Asíwájú | Position established |
Arọ́pò | Mustapha Amin |
Governor of the Northeastern State | |
In office 1 Oṣù Kẹjọ 1975 – 3 Oṣù Kejì1976 | |
Asíwájú | Musa Usman |
Arọ́pò | Position abolished |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kejìlá 1942 Daura, Northern Region, Nigeria[1][2] (now Daura, Katsina State, Nigeria) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Safinatu Yusuf (m. 1971; div. 1988) Aisha Halilu (m. 1989) |
Àwọn ọmọ | 10 |
Alma mater | Nigerian Military Training College Mons Officer Cadet School U.S. Army War College |
Website | Official website |
Military service | |
Nickname(s) | Baba go slow[3][4] |
Allegiance | ![]() |
Branch/service | ![]() |
Years of service | 1961–1985 |
Rank | Major General |
*Yemi Osinbajo served as Acting President from 19 January 2017 – 13 March 2017 and 7 May 2017 – 21 August 2017 while Buhari received medical treatment. |
Igbesi aye teteÀtúnṣe
A bí Muhammadu Buhari sí ìdílé Fulani ní ọjọ 17 Kejìlá 1942, ní Daura, Ìpínlè Katsina[8], baba rẹ ni Hardo Adamu, ẹni tí ó jẹ́ olori Fulani, orúkọ ìyá rẹ̀ sì ni Zulaihat, ẹni tí ó Hausa.[9][10] Òun ni ọmọ kẹtalelogun bàbá rẹ̀. Ìyá Buhari ni ó tọ dàgbà, bàbá rẹ̀ fi ayé sílè nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rinrin[11].
Ìgbésí ayé rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi OlógunÀtúnṣe
Buhari dara pò mó Nigerian Military Training College (NMTC) ní ọdun 1962, ó jẹ́ omo odun kan dínlógún nígbà náà.[12] Ní oṣù kejì ọdún 1964, a yí orúkọ ilé-ìwé ológun náà padà sí Nigerian Defence Academy (NDA).
Ní àárín 1962 sí 1963, Buhari kó nípa ìmò ogun ní Mons Officer Cadet School ní ìlú Aldershot, England.[13] Ní oṣù kínní ọdún 1963, nígbà tí Buhari jẹ́ ọmọ ọdún ogún, a sọ́ di lieutenanti kejì.
Àwọn ÌtókasíÀtúnṣe
- ↑ "Muhammadu Buhari Presidential Candidate". thisisbuhari.com. Retrieved 8 February 2015.
- ↑ "Muhammad Buhari". Enyclopaedia Britannica. Retrieved 8 February 2015.
- ↑ Magnoswki, Daniel. "Buhari Goes From Nigeria's Change Champion to 'Baba Go Slow'". Bloomberg. Retrieved 6 September 2015.
- ↑ Buhari, Muhammadu. "From Baba Buhari Am Now Being Called Baba 'Go Slow' – 22/07/15". YouTube. Retrieved 6 September 2015.
- ↑ Abang, Mercy (2019-05-29). "Nigeria's Muhammadu Buhari sworn in for second term as president". Google. Retrieved 2019-09-24.
- ↑ "Military Regime of Buhari and Idiagbon, January 1984 - August 1985". Retrieved 12 September 2013.
- ↑ Max Siollun (October 2003). "Buhari and Idiagbon: A Missed Opportunity for Nigeria". Dawodu.com. http://www.dawodu.com/siollun3.htm. Retrieved 12 September 2013.
- ↑ The Guardian: "Muhammadu Buhari: reformed dictator returns to power in democratic Nigeria" by David Smith 31 March 2015
- ↑ "Muhammadu Buhari Presidential Candidate". thisisbuhari.com. Archived from the original on 16 January 2016. Retrieved 8 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Muhammad Buhari". Encyclopaedia Britannica. https://www.britannica.com/biography/Muhammadu-Buhari. Retrieved 8 February 2015.
- ↑ "Exclusive Interview With GMB – Buhari speaks to The Sun Newspaper".
- ↑ Obotetukudo, Solomon (2011). The Inaugural Addresses and Ascension Speeches of Nigerian Elected and Non elected presidents and prime minister from 1960 -2010. University Press of America. p. 90.
- ↑ The Times, "US overtakes Britain at educating leaders" (September 5, 2019), pg. 19