Aníbal António Cavaco Silva, GCC (Pípè ni Potogí: [ɐˈnibaɫ kɐˈvaku ˈsiɫvɐ]; born 15 July 1939), ni Aare orile-ede Portugal. O bori ninu idiboyan aare Portugal to waye ni 22 January 2006, o si tun je titun-diboyan ni 23 January 2011, fun igba keji odun marun. Cavaco Silva bura ni ojo 9 March 2006.

His Excellency

Aníbal Cavaco Silva

GCC
Aníbal Cavaco Silva Senate of Poland 01.jpg
Aare ile Portugal
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
9 March 2006
Alákóso Àgbà José Sócrates
Pedro Passos Coelho
Asíwájú Jorge Sampaio
Alakoso Agba ile Portugal
Lórí àga
6 November 1985 – 28 October 1995
Ààrẹ António Ramalho Eanes
Mário Soares
Asíwájú Mário Soares
Arọ́pò António Guterres
Alakoso Eto Inawo
Lórí àga
10 January 1980 – 12 January 1981
Alákóso Àgbà Francisco de Sá Carneiro
Diogo de Freitas do Amaral (Acting)
Asíwájú António Sousa Franco
Arọ́pò João Morais Leitão
Omo Ileigbimo Asofin
Lórí àga
13 November 1980 – 30 May 1983
Lórí àga
4 November 1985 – 26 October 1995
Constituency Lisbon
Personal details
Ọjọ́ìbí 15 Oṣù Keje 1939 (1939-07-15) (ọmọ ọdún 80)
Boliqueime, Portugal
Ẹgbẹ́ olóṣèlu Social Democratic Party
Spouse(s) Maria Alves da Silva
Children Patrícia
Bruno
Residence Belém Palace
Alma mater Technical University of Lisbon
University of York
Profession Economist
Lecturer
Financial adviser
Signature
Website Official website


ItokasiÀtúnṣe

Àdàkọ:Cold War figures