Pedro Manuel Mamede Passos Coelho (Pípè ni Potogí: [ˈpeðɾu mɐnuˈɛɫ ˈpasuʃ kuˈeʎu]), (bíi ní Coimbra, ní Ọjọ́ kẹrìlélógún Ọsù keje Ọdún 1964) jẹ̣́ ọmọ orílẹ̀-èdè Portugal tó jẹ́ olùdarí ilé-iṣé, olóṣèlú, ààrẹ ẹgbẹ́ Social Democratic Party àti alakóso àgba orílẹ̀ èdè Portugal tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀.[1]

Pedro Passos Coelho
Alákóso àgbà orílẹ̀ èdè portugal
In office
Ọdún 2011 – Ọdún 2015
ÀàrẹAníbal Cavaco Silva
AsíwájúJosé Sócrates
ConstituencyVila Real
In office
4 November 1991 – 23 October 1999
ConstituencyLisbon
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí24 Oṣù Keje 1964 (1964-07-24) (ọmọ ọdún 60)
Coimbra, Portugal
Ẹgbẹ́ olóṣèlúSocial Democratic Party
(Àwọn) olólùfẹ́Fátima Padinha (Divorced)
Laura Ferreira
Àwọn ọmọJoana
Catarina
Júlia
Alma materUniversity of Lisbon
Lusíada University
ProfessionEconomist
WebsiteOfficial website

Àwọn ìtọ̣́kasí

àtúnṣe